Woro

Ẹsin to si iwájú nlo gba fe
Ẹsin to si iwájú nlo gba fe o
Ẹyin tẹn se ètò ẹgbẹ' fe fun
Igbá funfun lori omi,igbá funfun lori omi ó
Ẹniba mọ wẹ ko ka lọ
Ẹsin to si iwájú nlo gba fe
Ẹsin to si iwájú nlo gba fe o
Ẹyin tẹn se ètò kẹgbẹ' fe fun
Igbá funfun lori omi,igbá funfun lori omi ó
Ẹniba mọ wẹ ko ka lọ

Ori ọmọ lo shọ ọmọ,ìyá ati bàbá ọmọ
Lo kò ọmọ yọ ó,ọ'tá o gbero wípé koda
Igbá funfun lori omi,igbá funfun lori omi ó
Ẹniba mọ wẹ ko ka lọ

Ori ọmọ lo shọ ọmọ,ìyá ati bàbá ọmọ
Lo kò ọmọ yọ ó,ọ'tá o gbero wípé koda
Igbá funfun lori omi,igbá funfun lori omi ó
Ẹniba mọ wẹ ko ka lọ
Asalamu alekun ó,gbogbo èkó fẹdira o(gbogbo èkó fẹdira o)
Asalamu alekun ó,gbogbo èkó fẹdira o(gbogbo èkó fẹdira o)

Ológbowó se ti ẹ,o perengede (perengede)
Ìsàlẹ' ọ'fín ṣe ti ẹ,o perengede (perengede)
Ìsàlẹ' èkó ṣe ti ẹ o perengede (perengede)
Ẹ'pẹ'tèdó ṣe ti ẹ,o perengede (perengede)
Lafíàjí ṣe ti ẹ,o perengede (perengede)
Kampus o ṣe ti ẹ,o perengede (perengede)

Igi gbogbo,igi gbogbo ni so owó ọ tọ ní t'obì
Ológbowó ọ tọ,òkè poopo ọ tọ
Ẹ ri oko faaji kẹ de ọna ọlà ó
Kabo ó Kabo,kabo ó kabo
Oko faaji ta jo de o kabo o

Mo ki ení,mo kejì,mo kẹta ọ'rọ' gbenu ọlọ'rọ' má le sọ
Kabo ó Kabo,kabo ó kabo
Oko faaji ta jo de o kabo o
Ọmọ èkó fediral mio,lọkunrin lobinrin gbogbo wá
Ase odun yii a o se ẹmì tọmo-tọmo
Igunnugun ki pa ọdún jẹ ó
Ala ri ọdún,ọdún yí lowo l'ọmọ làlàáfíà ara
Gbogbo wa la o se pupọ ọdun l'ayé ó Ayinde ó

Igi gbogbo,igi gbogbo ni so owó ọ tọ ní t'obì
Ológbowó ọ tọ,òkè poopo ọ tọ
Ẹ ri oko faaji kẹ de ọna ọlà ó
Kabo ó Kabo,kabo ó kabo
Oko faaji ta jo de o kabo o



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link