Asikiri

Ẹ jẹ ka fi asikiri kọ rà wà kewu (kewu)
Ìbà ẹyin aliu lamọu warasatul anbiyai (anbiyai)
Mọ júbà ẹyin aliu lamọu warasatul anbiya (anbiyai)
Ẹyin làròlé bàbá Fatimo mi Muhammo (Muhammo)
Ẹyin làròlé bàbá Fatimo mi Muhammo (Muhammo)
Ẹyinjú Anọbi, bàbá Fatimo mi Muhammo (Muhammo)

Wa Yarobi Ansurini wa Nasira Nasisa bijahi Rosulu'llah Wa Musa kasa Yisa
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)

Ọlá Ọlọ'run Ọba mí pọ, b'ọlá alaurabi tí tóbi tó
O se ọlá Musa, ọlá Yisa, ó ṣe Sulaimona
Ó se ọlá Dauda, Owa se ọlá anọbi Muhammadu
(Sala Allahu Alei Wa Sallam)
Wali Musitafa Akehinde gbẹgbon o (Sala Allahu Alei Wa Sallam)
Baba Fatimo (Sala Allahu Alei Wa Sallam)

Olúwa, ó sá ti mọ pé ín lẹ nìkan Olúwa o
Ó Kúkú ti mọ pe ín lónà méjì
Lo fí gbe ere fuji yí lé mi lọ'wọ'
Ma se jẹ' ère nà ó bá jẹ mọ mí lọ'wọ' (Àmín oga wá)
Ẹyin eeyan mí ẹ jẹ ada waka
Fun Muhammo o nisẹ ńlá (o nisẹ ńlá)
Rosulu'llahi o nisẹ ńlá (Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)

Mo lẹ'ẹyin eyan mi
Ẹ jẹ ada waka fun Muhammo (o nisẹ ńlá Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)
Akẹyin de gbẹ gbọn baba Fatimo ọrẹ Ọlọhun (o nisẹ ńlá,Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)
Ikẹ ati ọla ko ma bá ń ìlú Medina amin (o nisẹ ńlá, Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)
Ohùn leni ta o ba ó ti gbogbo àyè ń jẹ'ran ẹ ni (o nisẹ ńlá,Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)

Rọbana rọbali alaiki, Rọbana rọbali alaiki
Najina min sari samani, Najina min sari samani
Wa gina min kasa lamọta watina min kasa adata
Waridọ mọn ana ili'lamoni, Waridọ mọn ana ili'lamoni
Sheu Sulemọna Faruk mí, Ali miskin Bi'llahi mi
Oko iya Ramọta Kehinde

Baba Mariam,baba Idayatu'lahi ẹ ku isẹ
Asikiri fún oni se ńlá (Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)
Iná mí Sulemọna mí, Wa inahu Bisimillahi mí amin
Sulemọna ọrẹ Ọlọhun, mọ kí ẹ ku isẹ asikiri
Sheik Isiaka, ọmọ agbarigi doma pẹ'lú mai fu Allah
Ẹ ku isẹ asikiri fún oni se ńlá (Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)

Amir Awolabi Kazeem mi, Sheik Arisukuna Suraju
Pẹ'lú C Nureni ẹ má ku isẹ ti asikiri fún oni se ńlá (Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)
Isibulahi ni ìjọ wa àti Alfa ńlá
Sheik Atanda Suraju Sanusi

Atanda ọmọ òkò ẹ ku isẹ t'asikiri fún oni se ńlá (Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)
Sheik sul Kanai nimi àkèré korò yo kòkò
E yí to ti da kò ní ba jẹ, ẹ kú isẹ asikiri fún oni se ńlá (Rosulu'llahi o nisẹ ńlá)

Alubarika mo tọ rọ (alubarika mo tọ rọ)
Alubarika mo tọ rọ (alubarika mo tọ rọ)
Ẹ'mí gígùn mo tọ rọ (ẹ'mí gígùn mo tọ rọ)
Àlàáfíà mo tọ rọ (àlàáfíà mo tọ rọ)
Àlàáfíà mo tọ rọ (àlàáfíà mo tọ rọ)
Àlàáfíà mo tọ rọ (àlàáfíà mo tọ rọ)
Ẹ'mí gígùn mo tọ rọ (ẹ'mí gígùn mo tọ rọ)
Alubarika lo ń wá (alubarika lo ń wá)
Alubarika lo ń wá (alubarika lo ń wá)



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link