Classical Fuji, Pt. Three

Joel ọmọ t'ajayi
Sanmi, ohun gbogbo lo lásìkò
Asiko kan ama bẹ o
Awọn àgbàlagbà

Awọn àgbàlagbà lo sọ bẹẹ
Wọn ni ohun gbogbo lo lásìkò
Igba kíkan wá, iyẹn fun'lé
Igba gbígbé, owá ìyẹn fun'lé
Igba sise, igba jíjẹ o, igba mi mu o
Igba nina, igba li lo
Igba to wa'ndun yii
Awa bẹ ọ elédùmarè ko ma se fí kikan si
Ajokẹ Rashidatu ọmọ toke Ìbàdàn
Nile Oluyole o
Ọrẹ mi Ajokẹ Ade

Tori pe apọnle lara fe
Ara o fẹ àbùkù
Ẹyan to ba ponmile ọmọ gbolahan mi
Ma ya ta apọnle gidi-gidi fun
Kabiyesi elegusi ọba Demola



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link