Adura Lebo

Ta lo ru ẹrù ti o mọ', ìyá ǹ jẹ' (ìyá ǹjẹ')
Ta lo ru ẹrù ti o mọ', ìyá ǹ jẹ' (ìyá ǹjẹ')
Atẹki,atẹki,atẹki,atẹki,atẹki at'ajá ó
Ẹran ìkokò ni (Ẹran ìkokò ni)
Atẹki,atẹki,atẹki,atẹki,atẹki at'ajá ó
Ẹran ìkokò ni (Ẹran ìkokò ni)

Moń kí yín ó, ẹwẹso onílé (ẹwẹso onílé)
Moń kí yín ó, ẹwẹso onílé (ẹwẹso onílé)
Mo ma ń kí yín ó, ẹwẹso onílé (ẹwẹso onílé)
Àwa la ń lù ìlú, ìlù dakun ma lù wa o
Ọba lọ ń fi isẹ yín ní
Àwa la ń lù ìlú, ìlù dakun ma lù wa o
Ọba lọ ń fi isẹ yín ní

Èrò tí ń lọ s'okò se pẹlẹ (se pẹlẹ)
Èrò tí ń lọ s'okò se pẹlẹ(se pẹlẹ)
Sọra fún pakùté ọdẹ se pẹlẹ (se pẹlẹ)
Ma sọra fún pakùté ọdẹ se pẹlẹ (se pẹlẹ)
Ẹranko ní wọn dẹ sì lẹ fún se pẹlẹ (se pẹlẹ)
Ìran ẹranko ní wọn dẹ sì lẹ fún se pẹlẹ
(Se pẹlẹ)
Komá padà wa mú ènìyàn o se pẹlẹ (se pẹlẹ)

Ìyá alátẹ ó sin lè, Ìyá alátẹ ó sin lè
Ìyá alátẹ ó sin lè, Ìyá alátẹ ó sin lè
Bẹẹni, Ìyá alátẹ ó sin lè, Ìyá alátẹ ó sin lè
Àjò tó gbe ọjà lọ ìdùnnú ni o babọ
Ìyá alátẹ ó sin lè

Àjò tó gbe ọjà lọ ìdùnnú ni o babọ
Ìyá alátẹ ó sin lè
Isẹ orí rán mí moń jẹ (moń jẹ)
Alayinde o, isẹ orí rán mí moń jẹ (moń jẹ)
Ọ'rọ' mí ní, ọrọ' orí rán mi moń jẹ (moń jẹ)
Isẹ orí rán mí moń jẹ (moń jẹ)
Isẹ orí rán mí moń jẹ (moń jẹ)

Ìgbéraga là fe mi, ko ma da
Ìgbéraga là fe mi o, ko ma da
Ọlọhun Ọba lọ ń jẹ emíní emíní
Af'emi af'eniyan, af'eniyan af'ọlọhun
Atẹ rẹrẹ ka rí ayé
Af'emi af'eniyan, af'eniyan af'ọlọhun
Atẹ rẹrẹ ka rí ayé
Orí gbogbo má dá tọ'lọhun ọba ní
Ohun lọní mimọse lọdọ
Ta fin jẹ ba se ń jẹ

Af'emi af'eniyan, af'eniyan af'ọlọhun
Atẹ rẹ rẹ ka rí ayé
Bi mo jí l'òwúrò má sọpẹ
Bí ń ba jí l'owuro ma sogó
Bi mo jí l'òwúrò má sọpẹ
Bí ń ba jí l'owuro ma sogó
Lọ'wọ alaurabi to da ni s'ayé
Lọ'wọ alaurabi to sẹda mi ò
Bi ń bá jí l'òwúrò má sọpẹ

Afi olọhun afi ènìyàn tí mo gboju le o
(Afi olọhun afi ènìyàn tí mo gboju le)
Ayinde o gun
Afi olọhun afi ènìyàn tí mo gboju le o
(Afi olọrun afi ènìyàn tí mo gboju le)
Ọjọ' mo ti dáyé Ayinde kò si ẹnikan
(Afi olọrun afi ènìyàn tí mo gboju lè)
Moni lọ'jọ mo ti dáyé Ayinde kò si ẹnikan
(Afi Ọlọrun afi ènìyàn tí mo gboju lè)

Adua lẹbo mi (adua lẹbo mi)
Adua lẹbo mi o (adua lẹbo mi)
Adua lẹbo mi (adua lẹbo mi)
Emí o lóhùn méjì (adua lẹbo mi)
Mí o lóhùn méjì sẹ (adua lẹbo mi)
Gbogbo igba ni moń jí pe Ọlọhun Ọba mí
(Adua lẹbo mi)
Mí o lóhùn méjì (adura lẹbo mi)

Mo pe Ọlọhun Ọba mí l'òwúrò mo pè l'ọ'sán
(Adura lẹbo mi)
Odi lalẹ mo pé Ọlọhun Ọba mí
(Adura lẹbo mi)
Ohun lon ba mi se gbogbo ẹ
Ton bọ si lójojúmó (Adura lẹbo mi)
Mi mo se kọ ará mí
(Adura lẹbo mi)
Ìwọ Ọlọhun Ọba ní olu dá abobo mí

(Adura lẹbo mi)
Baye ba gbógun báń ba sare títí
(Adura lẹbo mi)
Ifoya o si fe mi ọmọ Ọlọhun Ọba àmín
(Adura lẹbo mi)
Emí o lóhùn méjì (adua lẹbo mi)
Kúò nbe (Adura lẹbo mi)
Mi o lóhùn méjì (Adura lẹbo mi)

Arabambi se normal, normal rẹpẹtẹ
O se normal rẹpẹtẹ
Arabambi se normal, normal rẹpẹtẹ
O se normal rẹpẹtẹ
Arabambi se normal, normal rẹpẹtẹ
O se normal rẹpẹ



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link