Mo L'Oluwa, Ohun To Mu Bale Ile

Ohun to mu balẹ ilẹ sáré pa ti é mejeji
Oni hun ti on le, bi nkan o le

Ohun to mu balẹ ilẹ sáré pa ti é mejeji
Oni hun ti on le, bi nkan o le

Irakita aiye yi po, ká ṣe jẹjẹ
Irakita aiye yi po, ká ṣe jẹjẹ
Ako m'ohun w'aiye, aki yo mú lo s'òrun
Vanity upon vanity
All is vanity

Ohun to mu balẹ ilẹ sáré pa ti é mejeji
Oni hun ti on le, bi nkan o le

Irakita aiye yi po ká ṣe jẹjẹ
Irakita aiye yi po ká ṣe jẹjẹ
Ako m'ohun w'aiye, aki yo mú lo s'òrun
Vanity upon vanity
All is vanity

Ohun to mu balẹ ilẹ sáré pa ti é mejeji
Oni hun ti on le, bi nkan o le



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link