EYIN EWE IWOYI
Eyin ewe iwoyi
Ema fakoko sofo
Tori ojo nlo
Ko duro deni kokon
Eyin ewe iwoyi
Ema fakoko sofo
Tori ojo nlo
Ko duro deni kokon
Atete sun, oun latete ji
Atete sun, oun latete ji
Feni to mo'yi ise
T'osi tun fe oun toda
Ise de omo alase je o
Owo mare omo alase la
Kinihun de afitan gbaju
Ade ori oki omo gbolahan mi
Ko yo teyekeye
Eyin ewe iwoyi
Ema fakoko sofo
Tori ojo nlo
Ko duro deni kokon
Apon nse, oyin nse
Oju oloko re
Opo oni woto woro
Atete keye pamu oo
Baba yin ti
Baba yin ti de
Ise logun ise oremi
Mu ra si ise, ojo nlo
Bi a ko ba reni feyin ti
Bi ole lari
Bi ako reni gbekele
Ama tera mose eni
Iya re le lowo
Ki baba oleshin leko
Bi o ba gboju lewon
Ike tan nimo so fun oo
Otito oro ama dabi isokuso
O ba teti beleje ko gbo mi dara dara
Se nkan to o ko ba jiya fun
Ki nle to jo
Ohun taba fara sise fun
A ma pe lowo eni jojo
Apa lara
Kupa ni ye ko
Taye ba nfe o eni
Bi o ba lowo tan
Won yo ma fe o lola
Iwo ti o wa ni ipo atata
Aye nye o si terin terin
Je ki o deni tin rago
Oo ri baye se nyimu si oo
Iku a ma so eni doga
Wa ko ko wo dara dara
To ba reni, opo eniyan
Won fi eko seriri
Iwo mase fara we won
Iya nbe fun omo ti o gbo
Fun omo tin sa kiri
Mafowuro sere oremi
Mura si ise ojo nlo
Ema ma da so fun ole
Ole o gbiyanju aje o
Ema ma da so fun ole
Ole o gbiyanju aje o
Oo ori mi mokuola oo
Ko ni buru
Enala gafuru
Rohimi erutuba
Oo ori mi mokuola oo
Ko ni buru
Enala gafuru
Rohimi erutuba
Baba yin ti
Baba yin ti de
Baba yin ti
Baba yin ti de
Kinihun oloolaju
Baba yin ti de
Aperan lai robe o
Baba yin ti de
Kinihun oloolaju
Baba yin ti de
Ko gbo ohun ti mo hun so
Baba yin ti de
Iye mi ajike mi ye la
Baba yin ti de
Aya kinihun oloolaju
Baba yin ti de
Ema fakoko sofo
Tori ojo nlo
Ko duro deni kokon
Eyin ewe iwoyi
Ema fakoko sofo
Tori ojo nlo
Ko duro deni kokon
Atete sun, oun latete ji
Atete sun, oun latete ji
Feni to mo'yi ise
T'osi tun fe oun toda
Ise de omo alase je o
Owo mare omo alase la
Kinihun de afitan gbaju
Ade ori oki omo gbolahan mi
Ko yo teyekeye
Eyin ewe iwoyi
Ema fakoko sofo
Tori ojo nlo
Ko duro deni kokon
Apon nse, oyin nse
Oju oloko re
Opo oni woto woro
Atete keye pamu oo
Baba yin ti
Baba yin ti de
Ise logun ise oremi
Mu ra si ise, ojo nlo
Bi a ko ba reni feyin ti
Bi ole lari
Bi ako reni gbekele
Ama tera mose eni
Iya re le lowo
Ki baba oleshin leko
Bi o ba gboju lewon
Ike tan nimo so fun oo
Otito oro ama dabi isokuso
O ba teti beleje ko gbo mi dara dara
Se nkan to o ko ba jiya fun
Ki nle to jo
Ohun taba fara sise fun
A ma pe lowo eni jojo
Apa lara
Kupa ni ye ko
Taye ba nfe o eni
Bi o ba lowo tan
Won yo ma fe o lola
Iwo ti o wa ni ipo atata
Aye nye o si terin terin
Je ki o deni tin rago
Oo ri baye se nyimu si oo
Iku a ma so eni doga
Wa ko ko wo dara dara
To ba reni, opo eniyan
Won fi eko seriri
Iwo mase fara we won
Iya nbe fun omo ti o gbo
Fun omo tin sa kiri
Mafowuro sere oremi
Mura si ise ojo nlo
Ema ma da so fun ole
Ole o gbiyanju aje o
Ema ma da so fun ole
Ole o gbiyanju aje o
Oo ori mi mokuola oo
Ko ni buru
Enala gafuru
Rohimi erutuba
Oo ori mi mokuola oo
Ko ni buru
Enala gafuru
Rohimi erutuba
Baba yin ti
Baba yin ti de
Baba yin ti
Baba yin ti de
Kinihun oloolaju
Baba yin ti de
Aperan lai robe o
Baba yin ti de
Kinihun oloolaju
Baba yin ti de
Ko gbo ohun ti mo hun so
Baba yin ti de
Iye mi ajike mi ye la
Baba yin ti de
Aya kinihun oloolaju
Baba yin ti de
Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.