Ololufe (feat. Wande Coal)

I can't believe that she don't
And the thing I believe go
She say W mo cold
O wa sọ pe W mi o cold o (P!)
Wanna be on your show
Wanna put me on your shoulder
O ma fàṣẹ, she can play with the wall
I dey fight you, gonna won with the wall

Layẹmi, sọ fun wọn mo nifẹ, mo nifẹ ẹ gan ni
Fine lady girl, you different, different gan ni o
I no know why but mo miss ẹ, mo miss ẹ gan ni o
Bad girl, I'm addicted, addicted gan ni o

Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)

(Hmm, sọ fun wọn mo n'ifẹ)
(Mo ni, Fọlashade)
(Sọ fun ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni o)

Layẹmi, Ọlayẹmi, mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Titilọla, hmm, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Mo ni, Fọlashade
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ife gan ni

Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ

Ko, ko, ko, ko
Konkobilo, ko-ko-ko
Ọwá fẹ pàdé mí ní ìsàlẹ̀
Òye ká fún konkobilo

Ko, ko, ko, ko
Owa fẹ jẹ ko-ko-ko-ko
Mo ni ko pàdé mí ní ìsàlẹ̀
Ìyẹn gan lo ṣe ko-ko

Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)

Layẹmi, Ọlayẹmi, mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ ẹ"
Titilọla, hmm, so fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Mo ni, Fọlashade
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni

Gbé mi de bẹ
Gbé mi de-, gbe-
Gbé mi de bẹ, de bẹ
Gbe-

Wọn lo wa ji (gbé mi de bẹ)
Wọn ní mo ji
Wọn ní pe mo ji
Ki ni mo de?
Ani kí ló gbé? (Gbe mi)
Wọn ni, "Ki lo wi?
Mo ni mo de
Wọn ni mi o dé

Mo gbéra dídé (gbe mi)
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé



Credits
Writer(s): Michael Collins, Wande Ojosipe
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link