O Fun Mi L'edidi, Ore-Ofe (Medley)

FILLED UNDER: O FUN MI LEDIDI

Camc Salvation14: 411 comment

O fun mi l'edidi,
'Gbese nla ti mo je,
B'o ti fun mi, o si rerin,
Pe, "Mase gbagbe mi!"

O fun mi l'edidi,
o san igbese na;
B'o ti fun mi, o si rerin,
Wi pé, "Ma ranti mi!"

N ó p'edidi na mo,
B'igbese tile tan;
o n so ife eni t'o san,
Igbese naa fun mi.

Mo wo, mo si rerin
Mo tun wo, mo sokun;
eri ife Re si mi ni,
N ó toju re titi.

Ki tun s'edidi mo,
Sugbon iranti ni!
Pe gbogbo igbese mi ni,
Emmanueli san.

Amin



Credits
Writer(s): Public Domain
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link