Akosile
akosile ti duro akosile o le tase oun toluwa base eda kan kole yi
pada ibi ori n gbe ni lo kese ma si ni lona oun to wun eleduwa lo le
yan fun wa atibi atire ton sele lala eda kole ye e e akosile ti duro
kole tase o o o, ayanmo eda ti duro kirakita o dola laye gbogbo eto
olorun kose ni tole ba tun to gbogbowa lan sare kiri pe ka lola ka
jeniyan sugbon ta lole mo ibi ori dawun si atibi atire ton sele lala
eda kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se,
wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye
mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.
Kadara eda ti duro ife eleda o le ye lai ona ti o ba wun olorun oun
lole mu ese eda to ori e o dade ofe jo ba o wa n ba yanmo jijakadi
boti wun e ni to dale lose n foyin si atibi atire ton sele lala eda
kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o,
eniyan ma yo ra leun koya gba folorun lo to womo meji tabi lojo kan
ayanmo ototo loyan onise ika n sorire onise re wan to si Awa bi
olorun lere bo se je boti wun oluwa lon soro kose ni tole da lejo
akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se o baba
koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.
Oro olorun ede ni ileri re ko le ye lai oun ti oluwa ba pinu ife ota
kan o le pada oti pinu pe ki sorire pe ki lola ki n jeniyan oun
toluwa ba ko ko seni to le yi bo ti wun oluwa lon soro oun lo layo
ati ola akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se,
wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire
ni kofimi da, wa ba mi se mo bebe,
iwo lo ran mi wa ba mi se kaye mi
ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.

Credits
Writer(s): Sola Allyson, Tolu Fafowora
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.