Jagua Nana
Jaguanana ooo
Sisí alájẹ'ṣẹ' ooo
Jaguanana ooo
Sisí o ní pangbé ooo
Gbogbo owó mi ló wá gbà tàn ooo x2ce
Èní ijó, ọ'lá party ooo
Èní ọtí, ọ'lá sìgá ooo
Kòkò ò tó ròfọ' jaguanana ooo
Kòkò ò tó ròfọ' ooo jaguanana
Kin wọ mọ'tò lo fẹ' tàbí kin rinsẹ' kú ni
Kin wọ mọ'tò lo fẹ' tàbí kin gun kẹ'kẹ' ooo
Ìyá mi á bèrè nílé ooo níbo ni mo lọ
Màmá mi á bèrè owó ò tí mo bá délé
Jaguanana oooo Sisí alájẹ'ṣẹ' oooo eee
Dayọ' á bínú jaguanana oooo
Bímpé á bínú jaguanana oooo
Ajénifújà á bínú jaguanana ooo
Níyì á bínú jaguanana oooo
ṣọlá á bínú jaguanana ooo
Ẹ'rí á bínú jaguanana ooo
Màmá á bínú tí mo bá délé ooo
Gbogbo òwó mi ló wá gbà tán ooo
Gbogbo ìkọ'kọrẹ' ló wá gbà tán ooo
Dede Àmàlà mi ló wá jẹ tán oooo
Èní ijo ọ'la party oooo
Irun orí gbó tán jaguanana oooo
Gbogbo eyín jó tán jaguanana oooo
Gbogbo ẹ'wù ló gbó ooo
Gbogbo bàtà ló fà ya
Bàtà ya tán gbogbo ẹ'wù lo gbó oooo
Ìyá mi á bèrè nílé ò pé bo ni mo lọ
Màmá mi á bèrè owó ò tí mo bá délé
(instrument)
Sisí alájẹ'ṣẹ' ooo
Jaguanana ooo
Sisí o ní pangbé ooo
Gbogbo owó mi ló wá gbà tàn ooo x2ce
Èní ijó, ọ'lá party ooo
Èní ọtí, ọ'lá sìgá ooo
Kòkò ò tó ròfọ' jaguanana ooo
Kòkò ò tó ròfọ' ooo jaguanana
Kin wọ mọ'tò lo fẹ' tàbí kin rinsẹ' kú ni
Kin wọ mọ'tò lo fẹ' tàbí kin gun kẹ'kẹ' ooo
Ìyá mi á bèrè nílé ooo níbo ni mo lọ
Màmá mi á bèrè owó ò tí mo bá délé
Jaguanana oooo Sisí alájẹ'ṣẹ' oooo eee
Dayọ' á bínú jaguanana oooo
Bímpé á bínú jaguanana oooo
Ajénifújà á bínú jaguanana ooo
Níyì á bínú jaguanana oooo
ṣọlá á bínú jaguanana ooo
Ẹ'rí á bínú jaguanana ooo
Màmá á bínú tí mo bá délé ooo
Gbogbo òwó mi ló wá gbà tán ooo
Gbogbo ìkọ'kọrẹ' ló wá gbà tán ooo
Dede Àmàlà mi ló wá jẹ tán oooo
Èní ijo ọ'la party oooo
Irun orí gbó tán jaguanana oooo
Gbogbo eyín jó tán jaguanana oooo
Gbogbo ẹ'wù ló gbó ooo
Gbogbo bàtà ló fà ya
Bàtà ya tán gbogbo ẹ'wù lo gbó oooo
Ìyá mi á bèrè nílé ò pé bo ni mo lọ
Màmá mi á bèrè owó ò tí mo bá délé
(instrument)
Credits
Writer(s): Orlando Julius
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
Altri album
- Ololufe
- Love, Peace and Happiness
- Ololufe
- Ololufe (feat. Seyi Shay) - Single
- Back To My Roots: The Very Best of Orlando Julius - Afrobeat, Funk, Soul & Highlife From The '60s-'80s
- Back To My Roots: The Very Best of Orlando Julius (Afrobeat, Funk, Soul & Highlife From the '60s-'80s)
- Jaiyede Afro (with the Heliocentrics)
- Disco Hi-Life
- Longevity and Reclamation, Vol. 5
- Afro Hi Life Classics, Vol. 2
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.