Lafia We Lawani

Yes sir
Like a this, like a that
Like a this, like a that
Like a you, like a this
Yeah

Shake your waist
Shake your ass
Shake your waist
Shake am, shake am, shake am
Yeah

Ẹ teti kẹ' gbọrọmí
Ija lode l'orin d'owé

Iyawo jowu o k'ẹru lọ
Làfià wé làwàní
Iyawo jowu o k'ẹru lọ
Làfià wé làwàní
Ija lode l'orin d'owé
Làfià wé làwàní
Ija lode l'orin d'owé
Làfià wé làwàní

Kòwò kòwò òju tiroko
Araba o wò mọ' ojuti wọn

Ekọ' o pé k'oyin ma duń mọ
Làfià wé làwàní
Ekọ' o pé k'oyin ma duń mọ
Làfià wé làwàní
Iyawo jowu o k'ẹru lọọ
Làfià wé làwàní
Ija lode l'orin d'owe
Làfià wé làwàní

Bí ina kú, a fìí eru boju
Ọgede kú, a f'ọ'mọ' rọ po

Oribúrúkú kí sé t'àwá
Làfià wé làwàní
Oribúrúkú kí sé te'yin
Làfià wé làwàní
Ija lode l'orin d'owe
Làfià wé làwàní
Iyawo jowu o k'ẹru lo
Làfià wé làwàní
Ekọ' o pé k'oyin ma duń mọ
Làfià wé làwàní

Yes sir
Like a this
Like a that (Lafia we lawani)
Like a this
Shake your waist
Shake your ass
Shake your waist (Lafia we lawani)

Take it boy

Yes sir!

Yes sir!
Like a this, like a that
Shake your w...
O pọ, o pọ, o pọ, o pọ, o pọ...



Credits
Writer(s): Victor Olaiya
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link