Awa Tunde Batinde

Óun gbọgbọ lọwọ orí
Ayìnde Wasiu mí ọmọ Anifowose
Ẹni orí bá bá ṣé ooo
Lọn t'aja lọn j'ere lọn lòwò lówó lọn m'owó wálé Wasiu
Ọmọ Anifowose ori
Àwa dúpé fún Ọlórun ọba ó
Berlin lawa yi ọmọ Anifowose ni Germany

Koyode mí Thompson, Femí ọmọ Shotire o
Andawa Sukura, mọ dùpé lòwò Ọlórun ọba
E ṣeun ṣeun mí
Awọ tí Alex Bodurin, awọ Adeola Alhaji mí
Gbọgbọ yìn eṣe mo dùpé
Ké bá mí tọju Abiodun ọmọ Gbajabiamíla mí
Àti Waheedi Bodi mí
Pẹlu Taiyelolu ọmọ Giwa Giwa awọ Ayìnde mí Wasiu
Ọkó Rashida Ololeya sweetie baby
Awọ Niyi om'Ojodu, ọkò Lady ko Mariam maya babam
Bàbá Suwe óun o mope, Ola bàbá Ṣukura
Tọju Kunle Kunle, awọ Saheed ọmọ Rufai
Pẹlu Waliu mí gbọgbọ yìn e ṣeun
E tọju Abosede baby ọmọ Ayoka mí Saliu
Ọmọ ti lo gọmọ lofin ni Ikorodu óò
Pessy Ademokun óò, tó bá ń gbó ní Nigeria awọ lọn pẹ orí awọ

Àní bí mọba kọrin tí tí tí
Un ò je gbàgbé awọ mí l'America
Awala san bano Wale ọmọ Balogun o
Ọkò Bolanle baby o, Lady Morayo mí bàbá Oyìnda o

Alao ọmọ Akindele
Ọkò Layide mí larufaya bàbá tonton
Demola ọmọ t'Oyefeso alaṣe ni Genesis
Bàbá Ololade ọmọ tún tún ó
Congratulations mí ó ṣeun bàbá Demola
Sikiru Fashek ó, ọmọ Fashola
Bàbá ejire ọmọ meji, ọkò Yetunde baby
Kó bá mí tọju Lola Lola, l'Ògbómòshó
Ìyẹn lolamo Ajala o

Mrs Adeniyi Badmus mí
Tó bá n gbó'hùn mí ní Chicago awọ lọn pé orí awọ
Awọ Enifeni Sikiru, ìyẹn ègbọn dodo ọmọ Omega
Sikiru ọmọ Enifeni, ọkọ' Ademífunbi Sekina o
Ayo ọmọ Sogunyi bó bá ń gbó ni Los Angeles
Ọkò Bolanle baby, má má rórẹ awọ lọ n pé orí awọ
Mélé gbà gbé ẹ láì láì

Ti n bá kọjá Darkin
Raimo Adeola
Ọmọ Akujore mí, mother Ayomade
Sulaimon Anifowose Yomade óò
Debo ọmọ Lamídi mí, At'Okanlawọn, ké bamí tọju chairman
Sakiru ọmọ Ajibola, ọkò Mojisola Ololeya, gbọgbọ won ni akinu Germany
Adio mí Monsuru, ọmọdun tó ń mí o ṣeun pẹlu láti Odunuga
Awọn àbúrò Yomi Yomi, oremí Olowu eye, ìyẹn ọmọ shogunbinikod
Awọ Mark Oyetunde, awọ China Owomape, awọ Kenny o kare China o

Tí n bá tún dé Belgium
Má rántí Dele Dele
Ogunkogbiti kogbiti ọmọ Ogunjimi, oyìnbo tó ń tá motor mí
Awọ Laye ọmọ Ayeni bi ọjó, ìyẹn Ìjèṣà ọmọ Eleni Atek ọmọ Eleni yemele
Mélé gbàgbé Mayor Azeez mí, Mayor n'ilu Belgium mí
Awọ Remi Alowonle, ọkó ka Ruka òkè Ibadan n'ile Oluyole ó
Imole Moshood ọmọ Onala mí, àbúrò ọmọ Bolaji
Nala tó dì olóògbé, Ọlórun bamí sara ba Onala ọmọ Bolaji

Ti n bá kọjá ní Amsterdam
Mélé gbàgbé é Tunji Tunji ọmọ Olaniran o, Kashokiofula ọmọ Olanihun
Àbúrò Gboye mí, Gbenga ọmọ Olanihun
Àbúrò Ọmọkayode ọmọ t'Olanihun, orí olówó ní London
Awọ Ayìnde, ti sawọ Olamípupo yẹ ó
Waka ọkò Ọlóruntoyìn mí, awọ tèmí Ayìnde
Awọ Murphy, ọmọ Mojuolape ọkò Sakiratu mí ọmọ Sanusi
Òkè Ibadan n'ile Oluyole o, Sakira baby ó
Awọ ti Sukanmími ọmọ t'Opadipe ó
Taiyelolu ọmọ Somide, Amsterdam
É bá mí tọju àbúrò mí Kolapo, àbúrò Yinka
Chief Mrs Akindele, ìyẹn áyá Dele Akinyele
Oto Akogun n'ilu Ikare, awọ Ayìnde óò
O ṣ'awọ Bobo e Femi Femi, é ṣeun
Sunday Jeje, gbọgbọ won n'ilu Amsterdam, ẹ má ṣe ọjọ

Má tárá ṣaṣa má sáré ló sí Espanyol
Màló rí Juliet baby, ọmọ Tenibokun
Ibini arogun tayo mí
Ní Bendel ṣá nílé wón l'Edo ó
Awọ Faith Yinka baby
E bá ń tọju Bukky mí, Bukky ni Madrid mí
Aburo Chief Femi Femi hero, Borokini of Lagos mí
Ọkò Oluwafunmí Aduke, Histon, Texas, magbó bí mó ṣé ń wí
Bukky, ẹ má kú itọju mí óò, ní Madrid
Juliet Tenibokun Ọlórun a dùró tí ẹ ó, ẹ má kú itọju ọba
Oluaye òní Fuji, Ayinde Ade

Gbọgbọ ero tọba re London, e bamí ki Yinka Agbekeade
Alfa Omega lọn kí ẹ bi etí é bá ń já
Awọ Barrister lawyer mí o
Titi baby, Titi Adeyemo
Ajadi Monsuri mí ọmọ Olumegbon
Adio Debayo mí ọmọ Kosoko King
Tunde Tunde mí Yinusa, bàbá Egunjobi, ema ku ìtójú ọba
Alade koma mí bi eti bá ń já marolẹ
Aburo mí Ayìnde mí Wasiu
Toju Deji mí connection tó ṣe iyawọ lojo si, ọmọ Olaribigbe

Omega lọn kí ẹ omega lọn kí ẹ óò
Èwo Wasiu mí Anifowose
Omega lọn kí ẹ ó omega lọn kí ẹ
Alfa omega o, omega lọn kí ẹ

Ọmọlabake Kaotharah, Ademíde b'eti ẹ bá ń já n'ile
Marorẹ o, ọkó lọn perí áyá o, mío pé kò kú, mío pe orun o
Ko bamí to ọmọmi atolàá, k'iwo gàn gàn kó gùn l'èmí
Abimo lè mọ ní tí egbeda, Labake Kaotharah mí
Àya Anifowose má gbó bi mọ ṣen wí

Omega lọn kí ẹ, omega lọn kí ẹ
Alfa omega o, omega lọn kí ẹ
Berlin lawa yí óò, ọmọ tó gbolahan mí, ọmọ Anifowose o ri

Torí sún sún l'áyé gbà, sún sún ṣa l'àyé
Sún sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣa l'àyé
Sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣá l'aye
Fuji dí sún sún Ayinde Wasiu
Sún sún ṣá l'àyé
Èyí ní new Fuji music ọmọ Anifowose ó rí
Sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣá l'àyé
Fuji tún tí sún s'iwaju Ayìnde Wasiu
Sún sún ṣá l'àyé
Alex Claire
Sún sún l'àyé ó gbá, sún sún ṣá l'àyé
Alex Claire
Sún sún l'àyé gbá, sún sún sa l'àyé
Sún sún l'àyé gbá, sún sún ṣá l'àye



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link