Efi Orin Ayo Gbe Wole

Ẹni a wí dé arábámbí Adegoroye ọkọ Fatia o
Al'ẹni a wí dé arábámbí Adegoroye ọkọ Fatia o
Ani ki ke ológbùró o o,e ma jọ tẹyẹ kẹyẹ nínú oko Ayinde mo tunde
Awa la ní ìlù,awa la lo orin
Ta n le mọ pọn bí ọlọmọ kò wá wi
Ẹni a wí dé arábámbí Adegoroye ọkọ Fatia o

Mon lọ so dé ẹ sìn mí Ayinde òdé ere ya o
Mon lọ so dé,mon lọ so dé
Ẹ sin mí Ayinde òdé ere ya
Mon lọ so dé ẹ sìn mí Ayinde ó òdé ere ya o
Mon lọ so dé,mon lọ so dé
Ẹ sin mí Ayinde òdé ere ya
Ayinde o bẹ ni kan sọ'tẹ'
Arábámbí o bẹ ni kàn sọ ọta o

Mon lọ so dé,mon lọ so dé
Ẹ sin mí Ayinde òdé ere ya
Alayinde o bẹ ni kan sọ'tẹ'
Arábámbí o bẹ ni kàn sọ ọta o
Mon lọ so dé,mon lọ so dé
Ẹ sin mí Ayinde òdé ere ya

Ìmọ̀ràn ọta oni jọ lórí mí o ó
Ìmọ̀ràn ọta oni jọ lórí mí o
B'ọta ba fò so kè bá ń ba bẹ jo lori
Tán ba pe ìṣubú mí làwọn wá kí rí arábámbí
Ọwọ t'ọ'gẹ'dẹ' ba nà so ke ara wọn ni wọn ó fí ṣe o
Ẹma bínú olúwa o,bàbá Adediwura ní mayegun

Adufẹ Alexander mí
Ẹnu ẹnu,ẹnu ẹnu
Ẹnu ẹnu,ẹnu ẹnu
Ní iran ẹsẹ' fi ń pá èkùró ojú ona o
Ayinde o tẹ lẹ yí pẹ-pẹ,pẹ-pẹ

Ìmọ̀ràn ọta oni jọ lórí mí o
Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n
Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n
Wọ́n fi ka se rawon ni
Ìmọ̀ràn ọta oni jọ lórí mí o
Bá a ba gbá lé,bá a bá gba ìta arabambi
Àatàn la da rí ìgbẹ' si o o
Ẹ sọrọ mi niwon kẹ dákẹ'
Ìmọ̀ràn ọta oni jọ lórí mí o
Ìmọ̀ràn ọta oni jọ lórí mí o

Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n o
Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n
Wọ́n fi ka se rawon ni
Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n
Wọ́n fi ka se rawon ni o
Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n o
Bi ọta mí pe ogún bá ń ba pe ọgbọ'n
Wọ́n fi ka se rawon ni



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link