Orun Oun Aye

Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re

Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Didara orun, o n so togo Re o Olorun
Ewa Re to yi aye ka, n so togo Re o bo ti po to

Gbogbo eda, eranko at'ewebe n yin O o
Ise owo Re gbogbo loke nile, won n yin O o Baba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re

Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kaja orun
Ipa ese Re, o n han l'ori apata
Esin Re n fogo yan, l'ori awon okun o Olola nla
Kini yo waa se mi, ti n o j'okele yo, ti n o ni le juba Re Oba

Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Gbogbo eemi inu mi, o n yin O yato o, Olorun mi

Iwo to mu mi la ina koja, to fi mumi goke, kini mba fi fun O
Kini mo to si ninu oore ofe ti mo ri gba lodo Re
O ba aye mi da majemu lati 'nu ole
Oro Re ye, o si se
Oba ti ki i dale oro Re
Iwariri ni n o ma fi juba Re o
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link