Nigeria the New Era, Pt. 3

Èní má dùn ó,ayé ẹwá bá wa ṣé ó
Èní má dùn ó,ayé ẹwá bá wa ṣé ó
Ayé ẹwá ba wa ṣé (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)
Bo l'òde s'òde

Gbogbo èkó olúọmọ (àmìlà)
Olúọmọ s'adúrà o (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìla)
Ko ní hun wá kò ní ọmọ (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)
Deyimika Oyekan mi (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)

Kabiyesi Adeyimika Oyekan (àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)
Eleko,bàbá Kolawole (àmìlà,bo l'òde s'òde àmìlà)
Bàbà Adeniran
Bàbá Barrister lawyer ton jẹ faládé (àmìlà)
À ṣe ọdún yi a ó ṣe èmi sí tọmọ-tọmọ (bo l'òde s'òde àmìlà)

Ọmọ Balufon ní mọ ọkọ' ní marò(àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)
Òkó obì fún òṣìkà ko fẹnu ẹ súre
Ọmọ Odiyan ọmọ ogún ni ìwáṣẹ'(àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)
Àfínju wọ ọjà arin gbé de ké ọbun wọja pa sio sio(àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)
Ọbun sio sio ní ru ẹrù àfínju wọlé (àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)

Ọmọ iroko lado,ọmọ Ọ'sanyìn lawẹ (àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)
Ọmọ oko wẹrẹ-wẹrẹ tode tí ìlàdo
Ti o ṣe fi ọkọ' ro,kò ṣe fi àdá ró
Oró ó kúrò n'idi ẹ (àmìlà bo l'òde s'òde àmìlà)
Ọmọ igi gbogbo kìkì ògùn(àmìlà)
Ojú awo ní bí ka ku (bo l'òde s'òde,àmìlà)
Òrìṣà oke ni kò gbọ' ohun ìkà(amila,bo l'òde s'òde,àmìlà)

Baba Kolawole,bàbá Deniran
Bàbá Barrister lawyer ton jẹ Falade (àmìlà,bo l'òde s'òde,àmìlà)
Èní má dùn ó,ayé ẹwá bá wa ṣé ó
Èní má dùn ó,ayé ẹwá bá wa ṣé ó
Ayé ẹwá ba wa ṣé (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)
Bo l'òde s'òde (àmìlà)

Chief Sakour Adesina ajọ sense
Sulaimon of Lagos ni bàbá olóyè (bo l'òde s'òde àmìlà)
Olorì Abioye Oyekan ni mama oloye
(amila,bo l'òde s'òde,àmìlà)
Mo la ṣe ọdún yi a là ṣe èmi sí tọmọ-tọmọ (àmìlà,bo l'òde s'òde àmìlà)
Gbogbo ìbílẹ' boys pátápátá ní ìsàlè ekó ẹ ma kú adúró ti (àmìlà,bo l'òde s'òde àmìlà)

Ibilẹ,ójoró mi jo ohun jo(ójoró mi jo,ohun jo)
Ojoró mi jo,ohun jo(ójoró mi jo,ohun jo)
Omi dúdú,omi dúdú (ohun jo)
Omi dúdú fo jù jọ aró (ohun jo)
Ó foju jọ aró ko le rẹ aṣọ (ohun jo)
Ko le rẹ aṣọ ko le rẹ àgbòn (ohun jo)
Kò ṣe rẹ kijipa awa (ohun jo)
Èé ojoró mi jo,ohun jo(ójoró mi jo,ohun jo)
Ojoró mi jo,ohun jo(ójoró mi jo ohun jo)

Gbogbo ibilẹ boys club tí isale èkó area pátápátá
Gbogbo yín ẹ seun ẹ ku a dúró tí olú ọmọ gbogbo t'ekó
Gbogbo ẹgbẹ' company ẹgbẹ' tèmi Ayinde Wasiu (ohun jo)
Chief Saliu Akamu Adetunji (ohun jo)
Chief Adenike Lawal ìyá lọ'já gbogbo èkó fediral (ohun jo)

Alimo Sadia aya ti Isola oloko (ohun jo)
Abẹjẹ Risikatu aya tí Isola lasisi (ohun jo)
Awo tí Amope Risika (ohun jo)
Chief Onifade Adisa Riliwanu (ohun jo)
Ọkọ Abikẹ Fausatu (ohun jo)
Cheif Dele Akinyele mi l'òndó (ohun jo)

Ọtun akogun gbogbo Ìkàré pátápátá (ohun jo)
Ààrẹ Ajadi mí savage ọkọ Mopelola Mufutiatu (ohun jo)
Architect Biodun ọmọ Fari (ohun jo)
Atanda Suraju ọmọ Sanusi (ohun jo)
Sheu Tijaniya moraba gbogbo yín ẹ kú àdúró mi (ohun jo)
Dapo ọmọ Balagun Dodo (ohun jo)
Aromirẹ Akuma (ohun jo)

Ọrẹ mí ó ku a dúró tì mi (ohun jo)
Ọlọhun Ọba apin ire kárí gbogbo wa Akeem Amao ọmọ aromirẹ (ohun jo)
Mo lo joró mi jo ohun jo(ójoró mi jo,ohun jo)
Ojoró mi jo ohun jo(ójoró mi jo,ohun jo)
Baba mí Ẹluku Gafari (ójoró mi jo,ohun jo)
Ẹku a dúró tì mi,bàbá ti Yinka Suraju (ohun jo)
Ojoró mi jo ohun jo(ójoró mi jo,ohun jo)

Ọba èkó lo fún l'olu ọmọ,ọba èkó lo fún l'olu ọmọ
Ọba èkó lo fún l'olu ọmọ,olu ọmọ L'ayinde Wasiu ó (ọba èkó lo fún l'olu ọmọ)
Deyimika ọba Oyekan ó (ọba èkó lo fún l'olu ọmọ)
Òní olú ọmọ L'ayinde Wasiu o (ọba èkó lo fún l'olu ọmọ)

Òní olú ọmọ L'ayinde Wasiu (ọba èkó lo fún l'olu ọmọ)
Ọba èkó lo fún l'olu ọmọ,ọba èkó lo fún l'olu ọmọ
Olú ọmọ L'ayinde Wasiu (ọba èkó lo fún l'olu ọmọ)
Olú ọmọ L'ayinde Wasiu (ọba èkó lo fún l'olu ọmọ)



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link