Ponmile

Mò lé t'ori ẹ wẹ l'okun o
Mò lé t'ori ẹ wẹ l'ọsa
Mò lé t'ori ẹ l'ogun opo (opo ina)
K'ọmọ aráyé rí mí pé well done sir

Pọnmile, pọnmile
Baby, pọnmile
Mà lọ l'ọkọ méjì
Torí o pẹ t'o sun'lé

Pọnmile, pọnmile
Baby, pọnmile
Mà lọ l'ọkọ méjì
Torí o pẹ t'o sun'lé

Mà lọ bá wọn d'adelebọ sí oo
Mà lọ gbọ, mà fún wọn l'ésì oo
Wọn bẹ ni Kogi, bẹ ni Lagos oo (yea, yea)
Mà lọ bá wọn d'adelebọ sí oo
Mà lọ gbọ, mà fún wọn l'ésì o
Wọn bẹ ni Kogi, bẹ ni Lagos o (wọnbẹ nibẹ, wọnbẹ nibẹ)

True love is hard to find, but I found you
L'ọjọ na mo pinu, I'll never hurt you
Kikẹ ni ma kẹ ẹ, nígbà ojo, nígbà ẹrun
Iwọ ni mo ń fín yangàn láwùjọ ọ
Iwọ l'ójú tí mò fi ń rírán

Pọnmile, pọnmile
Baby, pọnmile
Mà lọ l'oju méjì
O tí ṣé dí ẹ' t'o sun'lé

Pọnmile, pọnmile
Baby, pọnmile
Mà lọ l'ọkọ méjì
Mà lọ l'ọkọ méjì

Ma lọ, maa lọ
Ma lọ, maa lọ
(Uh-uh-uh)



Credits
Writer(s): Juwonlo Iledare
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link