Iba (Afuye Gege Oba)
iba re ni ma Faye mi ju
sin sin o lemi a figbamise
shebi yen noni iyen gangan sha loda mifun
eni ayeraye to ni gbami oo
ogo fo'oko re
afuye gege ti o se GBE
jigbini jigbini bi ate ileke
kabiyesi o mo se bare
oba to ju gbogbo oba lo
Mo seba re o mo seba re
Mo foribale mo gbowo soke
Mo seba re o mo seba re
Ni rele okan Mi ni mowari
Kaaaabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Emi seba re o mo seba re
Mo foribale Mo gbowo soke
Mo seba re o mo seba re
Nirele okan Mi Mani mowari
Kabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Talo le so talo le kawon
Awon irawo to wa loju orun
Egbe siro le won ke so fun wa
Awon erupe inu okun
Talo lo le so talo moye
Ewa iseda to yi waka
Iyanu fun dudu
Iyanu fun funfun
Ose feni togbon ateni Togo
Kaaaabiyesi o mo seba re oo
Oba to ju gbogbo oba lo
(Chorus and Bridge)
Gbogbo aye gbohun soke
Ninu ewa won fogo fun o'oko re
Ohun gbogbo fiyin fun o
Iwo nikan loba to logo
Oju Mi tiri eti Mi ti gbo
Iyanu re yi aye ka
Mogbo ninu eri awon eniyan mimo
Mori ninu itan emi gangan nitan
Ise owo re dada da ni
Aburu kankan o todo re wa
Ohun gbogbo lo le yi pada
Sugbon rara tododo re ko
Kaaabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo
(Chorus and Bridge)
Call: oba toju gbogbo oba lo
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: oba toju gbogbo oba laye eeee
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: kabiyesi o mo seba re o
Res: oba to ju gbogbo oba lo
Call: emi OMA fibukun fun o lojojumo Iwo nikan loniiii
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: nigbogbo igba nigbogbo asiko okan Mi yo ma fogo fo'oko re
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: oluwa orun aye ewa re yi ayeka won fogo fo'oko re
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: mo jewo mo jewo Iwo nikan loluwa ko selomi
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: You are beautiful beyond description ewa re koja ogbon ori
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: You are wonderful beyond comprehension Iyanu re koja Iyanu
Res: oba toju gbogbo oba loooooo
End
sin sin o lemi a figbamise
shebi yen noni iyen gangan sha loda mifun
eni ayeraye to ni gbami oo
ogo fo'oko re
afuye gege ti o se GBE
jigbini jigbini bi ate ileke
kabiyesi o mo se bare
oba to ju gbogbo oba lo
Mo seba re o mo seba re
Mo foribale mo gbowo soke
Mo seba re o mo seba re
Ni rele okan Mi ni mowari
Kaaaabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Emi seba re o mo seba re
Mo foribale Mo gbowo soke
Mo seba re o mo seba re
Nirele okan Mi Mani mowari
Kabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Talo le so talo le kawon
Awon irawo to wa loju orun
Egbe siro le won ke so fun wa
Awon erupe inu okun
Talo lo le so talo moye
Ewa iseda to yi waka
Iyanu fun dudu
Iyanu fun funfun
Ose feni togbon ateni Togo
Kaaaabiyesi o mo seba re oo
Oba to ju gbogbo oba lo
(Chorus and Bridge)
Gbogbo aye gbohun soke
Ninu ewa won fogo fun o'oko re
Ohun gbogbo fiyin fun o
Iwo nikan loba to logo
Oju Mi tiri eti Mi ti gbo
Iyanu re yi aye ka
Mogbo ninu eri awon eniyan mimo
Mori ninu itan emi gangan nitan
Ise owo re dada da ni
Aburu kankan o todo re wa
Ohun gbogbo lo le yi pada
Sugbon rara tododo re ko
Kaaabiyesi o mo seba re
Oba to ju gbogbo oba lo
(Chorus and Bridge)
Call: oba toju gbogbo oba lo
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: oba toju gbogbo oba laye eeee
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: kabiyesi o mo seba re o
Res: oba to ju gbogbo oba lo
Call: emi OMA fibukun fun o lojojumo Iwo nikan loniiii
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: nigbogbo igba nigbogbo asiko okan Mi yo ma fogo fo'oko re
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: oluwa orun aye ewa re yi ayeka won fogo fo'oko re
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: mo jewo mo jewo Iwo nikan loluwa ko selomi
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: You are beautiful beyond description ewa re koja ogbon ori
Res: oba toju gbogbo oba lo
Call: You are wonderful beyond comprehension Iyanu re koja Iyanu
Res: oba toju gbogbo oba loooooo
End
Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.