I Am with You

Jesu ni Balogun oko
E ma se je ka foya
Olutuko wa ni Jesu
Yoo mu oko wa gunle
'Gbati igbi aye yi ba n ja
Lor'okun ati ni'le
Abo kan n be ti o daju
Lodo Olugbala wa
E ma se beru
E kun fun ayo
Nitori Jesu loga oko
Bo ti wu ki iji naa le to
Yoo mu oko wa gunle
Metalokan Alagbara
D'abo bo awa omo Re
Lowo ategun ati iji
Je k'awa k'alleluia
Ogo ni fun Baba loke
Ogo ni fun Omo Re
Ogo ni fun Emi mimo
Metalokan lope ye
E ma se beru
E kun fun ayo
Nitori Jesu loga oko
Bo ti wu ki iji naa le to
Yoo mu oko wa gunle
E ma se beru (beru)
E kun fun ayo (ayo)
Nitori Jesu loga oko
Bo ti wu ki iji naa le to
Yoo mu oko wa gunle
E ma se beru
Do not be afraid
Nitori Jesu loga awako
Bo ti wu ki iji naa le to
Yoo mu oko wa gunle
Do not be afraid I am with you
Oh oh oh...



Credits
Writer(s): Joshua Tosh, Traditional Song
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link