Keys

Yeah (yeah)
The keys, keys to my heart, yeah
(It's Olumix Production)

Kọkọrọ, kọkọrọ ilé aiye' mí mò fí fún ẹ, ee-
Kọ'kọ'rọ tó ṣ'amona ẹ'dá, tó ṣ'àkóso ẹ'dá, mó fí jín'kí ẹ

Broken crayon can still color, oh-oh
I'm broken, but I'll stand up, eh-eh
Broken crayon can still color, oh-oh, oh
I'm broken, but I'll stand up, eh-eh, eh

You gat the keys to my heart
Má kojú mí s'orun alẹ (you gat the keys to my heart)
You gat the keys to my heart
Má kojú mí s'orun alẹ (you gat the keys to my heart)

Mà sọ mí dí, pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ
Pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ
Pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ
Pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ

Since I love you, (ah-ah, ah-ah) wanna raise a family with you
Mà fòyà, mà bẹ'rù, má ṣiyè méjì
Ìwọ l'alabaro mí

Broken crayon can still color, oh-oh
I'm broken, but I'll stand up, eh-eh
Broken crayon can still color, oh-oh, oh
I'm broken, but I'll stand up, eh-eh, eh

You gat the keys to my heart, má kojú mí s'orun alẹ (you gat the keys)
(You gat the keys to my heart)
You gat the keys to my heart (you gat the keys)
Má kojú mí s'orun alẹ (you gat the keys) (you gat the keys to my heart)
(You gat the keys to my heart)

Mà sọ mí dí, pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ
Pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ
Pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ
Pẹpẹyẹ owubanturu, o bímọ, kó rẹyìn p'ọmọ

Broken crayon can still color
I'm broken, but I would stand up
Broken crayon can still color
I'm broken, but I'll stand up
I'm broken, but I'll stand up

Credits
Writer(s): Alexander Ajifolajifaola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link