Emi Mimo

Emi mimo
Ekaabo
Ah, emi mimo
Eku ikale

Emi alaayo
Emi orun ooo
Adaba mimo
Eeeku ikale
Agbara to ju'aiye ati orun lo
Ekaabo
Ekaabo
Eku ikale

Ekaabo o
Eku ikale
Ekaabo o
Oh, eku ikale
Odeee lati wa so okun di ogo
Odeee lati wa so ekun di erin
Odeee lati was so ibanuje dayo

Eku ikale o
Ekaabo
Eku ikale o
Ekaabo oo
Baba eku ikale
Ekaabo
Emi mimo ti n so agbara di otun

Ogo kan to gbe aiye ati orun
Olowo ori awa oo
Ekun to koja gbogbo oke pata
Ode lati wa so ekun derin
Ode lati wa so egan di ogo
O ti de sarin wa oo

Eku ikale
Oti de sarin wa oo
Ema ku ikale o
Oti de sarin wa oo
Ema ku ikale oo
Eee emi mimo
Eee emi mimo
Adaba mimo odeee orun

Eku ikale
Ola san lo nile gbogbo eyan to n wo wa ebu ti yin
Erin po nile gbogbo eyan to n wo wa ema ko ti yin

Ekun tan, oshee gbe danu
Ogo bori ogun agbara ota kpin
Oti deee sarin wa o
Akani eleru, o yo de bo si n de
Emi mimo orun
Eku ikale
Emi alayo oo

Eku ikale oo
Emi olore
Eku ikale
Emi to n tan imole sipa okunkun ona
Ema ku ikale oo
Emi to shi ni ni iye lati mo oun to to ati oun to kan

Eku ikale
Emi to n so agbara di otun
Eku ikale
Emi to n so alaisan di alara pipe
Eku ikale oo

Emi to n so iku di iye
Emi to n so iku di ayoo
Oya emi to n shi ile omo
Ekaaabo oo
Emi to n shile omo fomo si meji, meta, merin
Emi to n so iku di aiye oo

Emi to n ji gbogbo oun to ti ku dide pata
Ekaaboo sarin wa
Ema ku ikale oo
Ekaaaabo sarin wa
Ema ku ikale
Eku ikale oo



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link