Logan Ti Ode

Emi mo oun oju mi ti ri
Mo mo oun eti mi ti gbo
Mo mo oun oju mi ti ri
Mo mo oun eti mi ti gbo

Logan t'o gbo iro ayo re o Olugbala, aye mi l'eto
Logan t'o gbo iro ayo re o Olugbala, aye mi l'eto

Mo mo oun aiye ma ti wi
Mo mo oun eniyan ma ti so
Won ti pe wa ni agan ri
Bo ya won ti pe o l'oloshi ri

Sugbon, Logan t'o de o Olugbala, l'aye mi l'eto
Sugbon, Logan t'o de yi o Olugbala, aye e l'eto

Aye t'o ti daru tele tele o-o, Logan ti o de
Oro t'eniyan ti fi s'alufaani re, Logan ti o de
Oro ti ko dara ti a ti so si o, Logan ti o de
Oruko to kii se ti e t'a ti pe o, Logan ti o de

Ani, Logan ti o de o Olugbala, aye e l'eto
Logan ti o de o Olugbala, aye e l'eto
Logan ti Jesu de Olugbala laye e l'eto

Ko s'oruko t'aye o le pe ni
Won a ma pe ni l'agan l'ona gbogbo
B'o ba lowo lo wo agan ni
B'o ba bi'mo o agan ni
B'o ba t'egbe, ko d'agba, agan l'oje

Sugbon Logan ti o de, so pe, Logan ti o de
Ani, Logan ti o de lesekese, Logan ti o de
Haaa, Logan ti o de o Olugbala, l'aye e l'eto
Logan ti o de o Olugbala, l'aye e l'eto

Instantly l'onje bee, Bo se n de bayi, won de yi oruko pada
Eh! Logan ti o de e-e-e (Logan ti o de)
Eni t'a pe l'agan e ma so wipe (Logan ti o de)
Awon t'a ti f'oruko aburu pe ni le won yi (Logan ti o de)
Ani, Logan ti o de o Olugbala (l'aye mi l'eto)
A-aye mi l'eto, Logan ti o de o Olugbala (l'aye mi l'eto)
Ani e-e, Logan ti o de o Olugbala (l'aye mi l'eto)
Ani, Logan ti o de o Aseda (l'aye mi l'eto)
Ani, Logan ti o de o Olorun o-o (l'aye mi l'eto)
Irawo owuro, Omo Mary, yo sinu oro mi (l'aye mi l'eto)
Alagbara ni Shiloh lo ba ranti mi si rere (l'aye mi l'eto)
Haa, enu mi wa kun fun erin o gbogbo (l'aye mi l'eto)
Aye mi gba iyipada otun o, Logan t'o de (l'aye mi l'eto)
Aye mi ba l'eto l'ota ba n wo iran mi (l'aye mi l'eto)
Aye mi l'eto l'ota ba n wo iran mi (l'aye mi l'eto)
Ota ka'wo ro enu won gbe tan l'ori oju kan (l'aye mi l'eto)
Haa, Ee, Logan ti o de e Olugbala (l'aye mi l'eto)
Thank You Lord Jesus for all that You are



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link