Oremi

Kowa joko ka soro
Ore mi, kowa joko ka soro
Kowa joko ka soro
Ore mi, kowa joko ka soro

Moji mo wo aye mi
Kini mo wa se? (Kowa joko ka soro)
Ore ko si mo fun mi
Kini o ku ninu aye (kowa joko ka soro)

Mofe dada fun ra mi
Igbadun 'nu aye (kowa joko ka soro)
Okan mi ni 'ronu mi
Agbara ni aye

Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)
Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)

Emi o ri ife pipo ninu aye
Ore dada ni mofe ninu aye
Emi o ri ife pipo ninu aye

Kowa joko ka soro
Ore mi, kowa joko ka soro
Kowa joko ka soro
Ore mi, kowa joko ka soro

Moji mo wo aye mi
Kini mo wa se? (Kowa joko ka soro)
Okan mi ni 'ronu mi
Agbara ni aye

Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)
Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)

O-o-o, emi o ri ife pipo ninu aye
Ore dada ni mofe ninu aye
O, emi o ri ife pipo ninu aye

Igadun fun aye, ore mi
Agbara fun aye, ore mi
Irorun fun eniyan to wa laye

Kowa joko ka soro
Ore mi, kowa joko ka soro
Kowa joko ka soro
Ore mi, kowa joko ka soro

Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)
Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)

Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí (kowa joko ka soro)
Ore mí, ore mí, ore mí, o-o-o
Ore mí, ore mí



Credits
Writer(s): Jean Louis Pierre Hebrail, Angelique Kidjo, Keith William Cohen
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link