Kárí

Mo mope wa Baba wa gba ope
Mo mope wa Baba wa gba ope
Mo mope wa Baba wa gba ope
Alaanu mi mo mope wa
Mo mope wa Alaanu mi mo
Mope wa, mope
Alaanu mi mo mope wa
Mo mope wa Baba wa gba ope
Mo mope wa Baba wa gba ope
Mo mope wa Baba wa gba ope
Alaanu mi mo mope wa
Alaanu mi mo mope wa
Alaanu mi mo mope wa
Mo mope wa

Mo dupe Jehovah mo dupe
Mo dupe Jehovah mo dupe
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Mo dupe Jehovah mo dupe
Mo dupe Jehovah mo dupe
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo

Jehovah lo ba mi se
Eledumare lo ba mi se
Atofarati lo ba mi se
O ti tan imole si ona mi
Mi o ni shi na

Ohun lo gba mi (gba mi)
Ogba mi o so mi daayomo
Otun tan imole so ona mi
Mi o ni shi na

Mo dupe Jehovah mo dupe
Mo dupe Jehovah mo dupe
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo

Ona ti o pe mi si ni mo n to
Ise ti o ran mi ni mo n se
Epe to mi ni mo je
Aye asu ese ko ma se de mi loona
Kin sa aseye aseyege ni wa ju re
Ona ti o pe mi si ni mo n to
Ise ti o ran mi ni mo n se
Epe to mi ni mo je
Aye asu ese ko ma se de mi loona
Kin sa aseye aseyege ni wa ju re

Mo dupe Jehovah mo dupe
Mo dupe Jehovah mo dupe
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo
Fun imole to tan si aye mi
Ose oo fun imole to tan si aye mi
Ose oo

Ohun mi aakari aiye ohun mi aakari aiye oo
Iran wo yio ma wa imuse yio je
Agbara yio ma so
Ohun mi aakari aiye oo

Ni iro ohun mi gbo gbo ese yio ma sare wa
Lati wa bao iwo ni kan lo ye mi ba
Ni iro ohun mi gbo gbo okan asi kpa ya
Lati ni irapada si igbalare
Ni iro ohun mi eti atebeleje
Lati gbo ohun re iwo ni kan lo ye mi gbo
Ni iro ohun mi oju a la si le ge de re o
Lati ri o Eni no to ye mi ri
Ni iro ohun mi gbo gbo ese yio ma sare wa
Lati wa bao iwo ni kan lo ye mi ba
Ni iro ohun mi gbo gbo okan asi kpa ya
Lati ni irapada si igbalare
Ni iro ohun mi eti atebeleje
Lati gbo ohun re iwo ni kan lo ye mi gbo
Ni iro ohun mi oju a la si le ge de re o
Lati ri o Eni no to ye mi ri

Ohun mi aakari aiye ohun mi aakari aiye oo
Iran wo yio ma wa imuse yio je
Agbara yio ma so
Ohun mi aakari aiye oo



Credits
Writer(s): Adewole Adesanya, Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link