E Wa Woo (with The Golden Mecury of Africa)

Nitori wipe, Sunny Ade tun gbe tuntun de
(E wa wo o)

Sunny Ade tun gbe tuntun de
(E wa wo o)
Nigba to lo to d'ariyanjiyan
(E wa wo o)

A gbe t'ana danu agbe tuntun le
(E wa wo o)
'Tori Okin l'oba eye l'oko
(E wa wo o)
Iji mere yi n ba ba won bo o
(E wa wo o)

A l'awon se'ka t'aba gba agbado o
(E wa wo o)
L'ori l'ade l'oga oni fila
(E wa wo o)



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link