Ina Ti E Da

Ina ti eda kin she fun wa rara
Ekeye magbo e fi na sanko yika
Akere wo ho e elefe fina Le jade
Òun ti o le bosi oun le n rawọ le
E le wa titi Oluwa o fún yín ṣẹ
Ayanmọ o gbo gun Ori lele jo

Ina ti eda kin she fun wa rara
Ekeye magbo e fi na sanko yi ka
Akere wo ho elefe fina le jade
Òun ti o le bosi oun le n rawọ le
E le wa titi Oluwa o fún yín ṣẹ
Ayanmọ o gbo gun Ori lele jo
Ayanmọ o gbo gun Ori lele jo
Ayanmọ lo n se daju ori lele jo
Ayanmọ o gbo gun Ori lele jo
Ìyẹn ti yemi yeke
Ori lele jo
Sunny ele ma ki o
Sunny ele ma ki o
Onishana ma ki o
Onishana ma ki o
Oni elewo e bimo
Oni elewo e bimo
Oni e showo e jeere
Oni e showo e jeere



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link