Iri

Gbe mi wo lotun mo tewo, iri ko se le mi o
Imole ko tan lotun sona mi
Itura ko ba le mi lati odo re
Gbe mi wo lotun mo tewo, iri ko se le mi o
Imole ko tan lotun sona mi,
Itura ko ba le mi lati odo re
Gbe mi wo lotun mo tewo, iri ko se le mi o

To mi sona lati rin, Olutona mi
Okunkun ko ka kuro, tan 'mole otun
Ki n rin lona naa t' O fe, oye ko ye mi
Maa rin, maa mo, oye a ye mi ninu Ife Re

Eni to ni emi mi gbe mi wo
Gbe mi wo lotun mo tewo, iri ko se le mi o
Imole ko tan lotun sona mi
Itura ko ba le mi lati odo Re
Gbe mi wo lotun mo tewo, iri ko se le mi o

Igba ti idanwo ba de o
Oluwa so mi
Ona maa su nigba mii, nigba ti ona mi ba su, Oluwa o
Adaba to mi
Imole lat' orun ko tan s'ona mi, ko maa tan nigba gbogbo o
Ona yen ko ma se di
Agbara laye atorun, owo Re lo wa, ko selomii leyin Re
Iwo nikan ni
Iwo nikan naa n mo fe, Oluwa
Saa ma to mi lo
Nigba ti o re okan mi o
Iri se le mi o



Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link