Ojumo Ire

Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
Aiku baale oro o yi o maje tiwa
Aiku baale oro o yi o maje tiwa
Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
abara tintin
Eeeeee abara tintin

Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
Aiku baale oro o yi o maje tiwa
Aiku baale oro o yi o maje tiwa
Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
abara tintin
Eeeeee abara tintin

Ojumo ireeeeeeeeeeee

Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo
Aiku baale oro o yi o maje tiwa
Aiku baale oro o yi o maje tiwa
Ojumo ire mo wa loni o ojumo ayo abara tintin



Credits
Writer(s): Oluwafemi Abolade Ogunleye
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link