Sa Gbekele

'Gbat a b'Oluwa rin
N'nu mole oro re
Ona wa yio ti ni mole to
'Gbata a ba nse 'fe Re
On yio ma ba wa gbe
Ati awon t'o gbeke won le

Ko s'ohun t'o le de
L'oke tabi ni'le
T'o le ko agbara Re l'oju
Iyemeji, eru, ibanuje, ekun
Ko le duro bi a gbekele

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

Ko si wahala mo
Tabi ibanuje
O ti san gbogbo gbese' wonyi
Ko si arokan mo, Tabi ifa juro
Sugbon bukun, b'a ba gbeke le

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

Ako le f'enu so
Bi 'fe Re ti po to
Titi a o f'ara wa rubo
Anu ti o nfihan
At'ayo t'o nfun ni
Je ti awon ti o gbeke le

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele



Credits
Writer(s): Tolu Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link