Animal Carnival

Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ

Magic and miracle plenty eh
Some dey close eye, others dey shine eye dey pray
In this land of confusion, big illusion
Baba Ìjẹbú tactics dem go use score hat trick
Dem go finger we brain, lie with no shame
Animal Carnival don start again

Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ

If say na Nollywood we for don clap
If say na comedy we for don laugh
36 million Naira snake swallow o
Monkey double am carry 70 go
Rat observe di matter plan him coup d'état
Di only way to the billions na chase out oga

Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ

Kùrù-kẹrẹ, kùrù-kẹrẹ
Àdán má ṣe (No Do)
Kùrù-kẹrẹ, kùrù-kẹrẹ
Kùrù-kẹrẹ, kùrù-kẹrẹ
Àdán má ṣe (No Do)
Kùrù-kẹrẹ, kùrù-kẹrẹ

Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ
Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Kò ṣe eku, kò ṣe ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ
Àdán ò ṣe eku, kò ṣ'ẹyẹ

Ọ'rọ' l'ẹyẹ n' gbọ'
Ẹyẹ ò dédé bà l'órùlé o
Ọ'rọ' ni
Ọ'rọ' l'ẹyẹ n' gbọ'
Ẹyẹ ò dédé bà l'orùlé o
Ọ'rọ' ni



Credits
Writer(s): Abiodun Oke, Adegoke Odukoya, Akin Akinhanmi, Akinkunmi Olagunju, Ayomiku Aigbokhan, Babajide Okegbenro, Dare Odede, Isaiah Odeyale, Olufemi Sanni, Opeyemi Oyewande, Peter Sadibo
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link