L'oruko Jesu

Ha Emi a dupe ore re oo
Ha emi a dupe ore re oo
M'ele sai dupe ore re oo
M'ele sai dupe ore re oo Baba
Ki le'ti wi

Ha emi a dupe ore re oo
Ha emi a dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo Baba
Ha emi a dupe ore re oo
Ha emi a dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo Baba

Ha ope lo ye
Ha ope lo ye
Mo wa laiye mo wa laiye eee
Ha ope lo ye
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo Baba
Ki le'ti wi

Ha emi a dupe ore re oo
Ha emi a dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo Baba

Jehovah Ide bube
Ne ba no ooo
Jehovah aaa ide bube
Jehovah
Jehovah ide bube
Ne ba no ooo
Jehovah aaa ide bube
Ne le'gwe
Ne le'gwe eee
Ibu eze
Ne lunwa aa
Ina cha chi iiii
Na la mu ooo
Ibu de ke na aa ya
Jehovah aaa
Ide bube
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo Baba
Ki le ti wi

Ha emi a dupe ore re oo
Ha emi a dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo
Me'ele sai dupe ore re oo Baba

Mimo Mimo Mimo Eledumare Oba alagbara giga giga aa
Oba to da wa si d'ojo oni ni
Ko jo si waju ko tun jo se'yin o
Ko jo sa'pa otun ko tun jo so'si o
Lati January o pawa mo o
Hey
Atun wo nu February O pa wa mo o
Atun wo'nu March O da wa si o
April May nko O da wa si o
June ko ju wa nu o da wa si o
July August nko O se wa lo go
September nko ko ba ibi le wa
October November nko ko ba ibi le wa
Atun wo nu December te'wo gb'ope e wa
L'odun titun ta wa yi wa se wa logo

L'oruko Jesu emi'olodun yi ja
L'oruko Jesu emi'o fa'yo lo ooo
L'ola a Jesu l'oke o dami loju ooo
Mi o ni fi ba nuje l'odun eyi oo
Eeeeeee

L'oruko Jesu n oo l'odun yi ja
L'oruko Jesu n oo fa'yo lo ooo
L'ola a Jesu l'oke o dami loju ooo
Mi o ni fi ba nuje l'odun eyi oo

L'oruko Jesu emi'olodun yi ja
L'oruko Jesu emi'o fa'yo lo ooo
L'ola a Jesu l'oke o dami loju ooo
Mi o ni fi ba nuje l'odun eyi oo
Eeeeeeee

L'oruko Jesu n oo l'odun yi ja
L'oruko Jesu n oo fa'yo lo ooo
L'ola a Jesu l'oke o dami loju ooo
Mi o ni fi ba nuje l'odun eyi oo

Ati ko nipa t'emi Itesiwaju ni t'emi
Ati ko ni pa t'emi aseyori ni t'emi
L'odun ti mow a yi se
Mio ni s'asedanu
L'ola Jesu loke n o l'odun yi ja
Eeeeee

L'oruko Jesu n oo l'odun yi ja
L'oruko Jesu n oo fa'yo lo ooo
L'ola a Jesu l'oke o dami loju ooo
Mi o ni fi ba nuje l'odun eyi oo

Ki nse nipa ipa
Ki nse nipa agbara
Bikose nipa emi e mi
Ni Oluwa Olorun n mi wi
Tani wo oke idiwo
T'onbe ni wa ju u mi
Tani wo oke idena oo
T'onbe ni wa ju u mi

Ka'gbeyin s'oke eyi ile gbogbo
K'oba ogo ko wole wa
K'agbeyin s'oke eyin idiwo gbogbo
K'oba ogo ko wole wa
Oluwa awon omo ogun sa ni oba ogo naaa
K'oba ogo ko wole wa
Gbogbo Idiwo Idena l'oju ona mi e pare patapata
K'oba ogo ko wole wa
L'oruko Jesu iji aiye mi da'ke je o
K'oba ogo ko wole wa
Tani oba ogo na Oluwa awon omo ogun ni o
K'oba ogo ko wole wa

Egbe orin yin s'oke gbogbo idiwo gbogbo o
K'oba ogo ko wole wa

Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
L'odun e leyi emi a se rere e
Emi ni n o la odun yi ja
Ajalu ibi ko ni de ba mi o
Emi ni n o la odun yi ja
L'oruko Oluwa emi a ta yo
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja

Gbogbo eyin omo Olorun
Olorun lo ranmi si o
Ninu odun eyi to wa yi
Oma s'aseyori oun rere ni
Oun to ba ti dawo le se
Oma yori si rere ni
Ahhh

Mo ti da wo le eooo
Jesu yio yanju re
Eeeeeeee

Mo ti dawo le oooo
Jesu yio yanju re

Mo ti da wo le eooo
Jesu yio yanju re

Mo ti da wo le eooo
Jesu yio yanju re

Eran ara ko le se ooo
Emi Mimo lo le se ooo

Eran ara ko le se ooo
Emi Mimo lo le se ooo

Eran ara ko oo le se ooo
Emi Mimo lo le se ooo
Eran ara ko le se ooo
Emi Mimo lo le se ooo

Bo ba wa ri be
Nitori Eledumare Oba algbara giga giga
Eru jeje Oba tin mi gbo kijikiji
Eru jeje L'olorun
Oba to da ogun Farao sinu ibu
Eru jeje oooo
Atari ajanaku koja eru t'omode ma gbe kari
Eru jeje o
Igba t'oba Soolu to k'oja aye re o j'iyan re nisu ni
Korah ati Datani d'ite mo Mose
Ile lo gbe won mi oooo
Ayagbayugbu oni'le ade wure
Oba to'nje Jehovah
Eru jeje ooo
Atari ajanaku ko ja eru t'omede ma gbe kari
Eru jeje ooo

Oke gbemi
Okuta we we we ni satani je ni waju Baba
Aramonka atofarati bi oke
Eni ti iku gb'oruko re ti ku pare
Eni ti aru gb'oruko re ti won sa lo
Eru jeje ooo
Atari ajanaku koja eru t'omode ma gbe kari
Eru jeje ooo

Oni kangunkangu
Akuwarape kogun s'oru
Jesu lo k'ogun si mi
B'aiye ba gbogun si mi a kuku pa won re
B'ota gba gbogbo ona agbe mi leke won oo
Eru jeje ooo
Atari ajanaku ko ja eru t'omode ma gbe kari
Eru jeje ooo

Eru ti aja yeri fun
Pepe ki o ru
Ara e mon gbo
Agbara esu da nibi Jesu gbe n j'oba
Ojo l'oko agbado
Se mo p'oba aiye a mon ku
Ijoye aiye a mon r'orun
Tani o gba pe Jesus ni ki nku
Atofarati bi oke oooo
Eru jeje ooo
Atari ajanaku ko ja eru t'omode ma gbe kari
Eru jeje ooo

Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja

Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja
Emi ni n o la odun yi ja



Credits
Writer(s): Akinsina Akinrodoye
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link