Ẹ̀bẹ̀ & Prayerś - Live
Oh Lord have come to seek ur face
Let your grace and mercy
Fall upon me Lord
Oh lord I call upon ur name
Let the rain of ur mercy
Fall upon me Lord
Ooooluwa mo wa sibi ite
Jeki ore ofe ati anu re ko balemi Lori
Ooooluwa mo ke pe oruko re
Jeki ojo anu re ko ro s'ori iseda mi
Babaaaa oooo eyi lebe
Baba alanu oo
Babaaa oooo
Olugbebe gbo ebe mi oluwa
Eyi l'ebe
Ayemi kobu ola fun o ni mo bere
Ona mi koto ninu ife re oluwa
Oooooooo eyi ni ebe
Gbami lowo asise oluwa
Gbami lowo Ogun tapa obimi oka
Gbami lowo Ogun Iran diran
Oluwa gba mioo baba
Eeeeyi lebe
Oluwa towo batinomiu afoju San
Babaaa oooo eeeyi lebe
Oba toji oku omo jairu dide
Oku lazaru ojo merin otira otin run
Iwo loji dide oluwa sanu mi
Jesu omo davidi gbo adura mi oluwa
Babaaa oooo eeeyi lebe
Lord I've come to seek ur face
Let ur grace and ur mercy
Ore ofe tomumi Debi
Koma pada leyin mi
Come upon me
Ooh Lord I call upon ur name
Let the rain of ur mercy
Fall upon me Lord
O ooooluwa Iwo to mumi Debi
Wa semi olododo
Let the rain of ur mercy
Fall upon me Lord
Babaaa oooo mo kigbe lohun rara
Si o latokun iseda mi oluwa
Eeeyi ni lebe
Baba alanu
Babaaa oooo
Ore ofere ni mo bere
Aye ose gbe lai so ore ofe re
Eeyi lebe
Ona maa su ni gbami
Nigba ti Ona mi ba su tun imole fun mi
Mi o ni fese ko ni irin timohun run
Iwo to Mumin Debi ose olododo Latin sun mi siwa ju
Eeyi lebe
Mogba agbara lowo alagbara pelu agbara re
Babaaa oooo eeeyi lebe
Ilekun toti kosi
Kilo ti ilekun kokuro nibe
Ilekun to ti kosi oluwa oo
Eeyi lebe
Awon towa ni ibi imole ko tan imole
Lori iseda mi
Babaaa oooo
Gbogbo ibi ti okunkun wa
Ki imole wole
Imole kowole ilekun toti kosi
Ilekun toti ko so
Kilo ti ilekun, ilekun toti kosi
Babaaa oooo
Ati rami pada
Moti di omo
I decree ilekun toti kosi
Eeeyi lebe
Adi ileri remu
Pewo yio wa pelu awa
To gbeke loruko re
Adi ileri re mu baba oni leri
Ti kin ye
Pewo yio wa pelu awa
To gbeke lorukore
Adi ileri re mu
Tani oke ni waju serubabeli
Pewo yio wa pelu awa
Oba onileri tikin ye
Ona abayo lodo re ju egbagbeje lo
Ona abayo lodo re ju egbagbeje lo
Kiloun ti ilekun
Ilekun kosi
Adi ilerire mu
Babaaa oooo
Pewo yio wa pelu awa
To gbeke lorukore
Adi ilerire mu
Amope Iwo yio wa pelu awa
To gbeke lorukore
Oniduro mi ESE oo
Oni duro mi ESE oo
Alanu mi ese oo
Irowo tofun mi ni irowo ese oo
To ba se eniyan loduro
Eniyan ti makun
Boba se eniyan loduro
Enyan ati ma saroye
Oni duro mi ese ooo
Oniduro mi ESE oo
Oni duro mi ESE oo
To ba se eniyan loduro
Eniyan ti makun
Boba se eniyan loduro
Enyan ati ma seregun
Oni duro mi ese ooo
Let your grace and mercy
Fall upon me Lord
Oh lord I call upon ur name
Let the rain of ur mercy
Fall upon me Lord
Ooooluwa mo wa sibi ite
Jeki ore ofe ati anu re ko balemi Lori
Ooooluwa mo ke pe oruko re
Jeki ojo anu re ko ro s'ori iseda mi
Babaaaa oooo eyi lebe
Baba alanu oo
Babaaa oooo
Olugbebe gbo ebe mi oluwa
Eyi l'ebe
Ayemi kobu ola fun o ni mo bere
Ona mi koto ninu ife re oluwa
Oooooooo eyi ni ebe
Gbami lowo asise oluwa
Gbami lowo Ogun tapa obimi oka
Gbami lowo Ogun Iran diran
Oluwa gba mioo baba
Eeeeyi lebe
Oluwa towo batinomiu afoju San
Babaaa oooo eeeyi lebe
Oba toji oku omo jairu dide
Oku lazaru ojo merin otira otin run
Iwo loji dide oluwa sanu mi
Jesu omo davidi gbo adura mi oluwa
Babaaa oooo eeeyi lebe
Lord I've come to seek ur face
Let ur grace and ur mercy
Ore ofe tomumi Debi
Koma pada leyin mi
Come upon me
Ooh Lord I call upon ur name
Let the rain of ur mercy
Fall upon me Lord
O ooooluwa Iwo to mumi Debi
Wa semi olododo
Let the rain of ur mercy
Fall upon me Lord
Babaaa oooo mo kigbe lohun rara
Si o latokun iseda mi oluwa
Eeeyi ni lebe
Baba alanu
Babaaa oooo
Ore ofere ni mo bere
Aye ose gbe lai so ore ofe re
Eeyi lebe
Ona maa su ni gbami
Nigba ti Ona mi ba su tun imole fun mi
Mi o ni fese ko ni irin timohun run
Iwo to Mumin Debi ose olododo Latin sun mi siwa ju
Eeyi lebe
Mogba agbara lowo alagbara pelu agbara re
Babaaa oooo eeeyi lebe
Ilekun toti kosi
Kilo ti ilekun kokuro nibe
Ilekun to ti kosi oluwa oo
Eeyi lebe
Awon towa ni ibi imole ko tan imole
Lori iseda mi
Babaaa oooo
Gbogbo ibi ti okunkun wa
Ki imole wole
Imole kowole ilekun toti kosi
Ilekun toti ko so
Kilo ti ilekun, ilekun toti kosi
Babaaa oooo
Ati rami pada
Moti di omo
I decree ilekun toti kosi
Eeeyi lebe
Adi ileri remu
Pewo yio wa pelu awa
To gbeke loruko re
Adi ileri re mu baba oni leri
Ti kin ye
Pewo yio wa pelu awa
To gbeke lorukore
Adi ileri re mu
Tani oke ni waju serubabeli
Pewo yio wa pelu awa
Oba onileri tikin ye
Ona abayo lodo re ju egbagbeje lo
Ona abayo lodo re ju egbagbeje lo
Kiloun ti ilekun
Ilekun kosi
Adi ilerire mu
Babaaa oooo
Pewo yio wa pelu awa
To gbeke lorukore
Adi ilerire mu
Amope Iwo yio wa pelu awa
To gbeke lorukore
Oniduro mi ESE oo
Oni duro mi ESE oo
Alanu mi ese oo
Irowo tofun mi ni irowo ese oo
To ba se eniyan loduro
Eniyan ti makun
Boba se eniyan loduro
Enyan ati ma saroye
Oni duro mi ese ooo
Oniduro mi ESE oo
Oni duro mi ESE oo
To ba se eniyan loduro
Eniyan ti makun
Boba se eniyan loduro
Enyan ati ma seregun
Oni duro mi ese ooo
Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.