Ta Lo Dabi Re?

Jehovah alagbara oba to tobiju, Kabiesi re o
Eni mimo julo ati alaanu julo, hosanna fun oruko re
Iwo apata wa ati ile iso wa, kabiesi re o
Awa juba re o, awa si foribale, iba re o, Iba re o

Oluwa talo dabi re laye lorun?, kosio komasi o
Oluwa talo dabi re laye lorun?, kosio komasi o

Angeli Won juba re lojo jo lorun,kabiesi re o
Kerubu oun serafu lorun yi ite re ka, hosanna fun oruko re
Ohun lo gbawala lowo isoro gbo gbo, awa yin o oluwa
Eni to kawaye ninu ife to gaju, hosanna si oluwa

Oluwa ko seni bi re laye lorun?, kosio komasi o
Oba ogo koseni bi re laye lorun,kosi o bi re

Aye nsa tatan pegan tesu si un hale, lalai o orore ayeIji
Iji aye banja, to kun re re si nrugo, lai lai o agbara re re

Oluwa talo dabi re laye lorun?, kosi o komasi o)

Oluwa o, oluwa o iyin ope nikan lo ye o o
Oluwa o, oluwa o iyin ope nikan lo ye o o
Awa niran ti nsaferi re, olorun to to o, olorun to po
Aseda wa o, olorun o, awa a gbohun wa soke si o
A gboju le o, a o ni jogun ofo, iwo la o sin titi aye wa
Oluwa o oluwa o, iyin ope nikan loye o o
Oluwa o oluwa o, iyin ope nikan loye o o
Awa niran ti nsaferi re, olorun to to o, olorun to po
Aseda wa o, olorun o, awa a gbohun wa soke si o
A gboju le o, a o ni jogun ofo, iwo la o sin titi aye wa

Oluwa talo dabi re laye lorun?, kosio komasi o
Oga ogo koseni bi re laye lorun?, kosio bi re

Credits
Writer(s): Bioku Llc
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link