Temitope
Baba baba o
Mo wa gbe baba
Mi ga
Ologun l'oluwa
Oluwa ni oruko re
Atininu ola nsola
Atininu imole s'ogo
Araba ribi oba mi
Alatise
Oba mi t'ofi Kiki imole bora bi aso
Ologo didan
Eleru niyin oba mi
Apa nla to s'ole aiye ro
Eru jeje leti okun pupa
Ologun niyin Oluwa
Alagbara niyin Oluwa
Oba mi alagbara
T'ofi agbara Gbani lowo alagbara
T'onfi agbara nini lara
Mo wa riri
Mo wa riri niwaju
Re Oluwa
Oba ar'ogun matidi
Ar'ogun ma ma s'ojo
Owo kembe re ibi jaa
Oba mi agbe ni nija
Ki eru ob'onija
Mo ti ri yin loju ise
Lalai mo ye igba o
Lori mi lori oko
Lori omo lori ijo
Lori gbogbo ebi
Ope ni mo mu wa Baba
Iyin lo ye o o
Wiwa l'aiye mi
Loni o
Anu re ni morigba
Baba
Temitope Ojuope lo
Temitope ojuope lo oo e
Temitope ojuope lo
Temitope ojuope lo oo e
Temitope ojuope lo
Anu Oluwa po laiye mi
Temitope ojuope lo
Oluwa dara si mi Temitope ojuope lo
Oluwa ra mi pada Temitope ojuope lo
Ogb'oju mi lowo omije
Temitope ojuope lo
Eeeeeeee
Oluwa korede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati
Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwamayomikun o
Oluwamayomide
Ayowoletomi
Ayomiposi Oluwafemi Oluwasegunfunmi o
Oluwamimodupe
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwa korede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Of'ire gbogbo wa miri o
Of'ire wa miri
Oluwasotemidayo
Oluwasotemidire
Oluwakemi Oluwatungbemiga o
Oluwajomiloju
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Temitope oo
Atofarati bi oke
Olowogbogboro
Agbanilagbatan
Temitope
Eeeee
Oro mi Tope
Temitope oo
Oluwaseun
Oluwamodupe o
Temitope
Oro mi Tope Temitope oo
Oluwaseun
Oluwamodupe o
Temitope oo
Oluwaseun
Oluwa e se o
Temitope oo
Oluwaseun
Oluwamodupe o
Temitope o
Oluwaseun
Oluwa ese o
Temitope oo
Oluwaseun
Mo wa gbe baba
Mi ga
Ologun l'oluwa
Oluwa ni oruko re
Atininu ola nsola
Atininu imole s'ogo
Araba ribi oba mi
Alatise
Oba mi t'ofi Kiki imole bora bi aso
Ologo didan
Eleru niyin oba mi
Apa nla to s'ole aiye ro
Eru jeje leti okun pupa
Ologun niyin Oluwa
Alagbara niyin Oluwa
Oba mi alagbara
T'ofi agbara Gbani lowo alagbara
T'onfi agbara nini lara
Mo wa riri
Mo wa riri niwaju
Re Oluwa
Oba ar'ogun matidi
Ar'ogun ma ma s'ojo
Owo kembe re ibi jaa
Oba mi agbe ni nija
Ki eru ob'onija
Mo ti ri yin loju ise
Lalai mo ye igba o
Lori mi lori oko
Lori omo lori ijo
Lori gbogbo ebi
Ope ni mo mu wa Baba
Iyin lo ye o o
Wiwa l'aiye mi
Loni o
Anu re ni morigba
Baba
Temitope Ojuope lo
Temitope ojuope lo oo e
Temitope ojuope lo
Temitope ojuope lo oo e
Temitope ojuope lo
Anu Oluwa po laiye mi
Temitope ojuope lo
Oluwa dara si mi Temitope ojuope lo
Oluwa ra mi pada Temitope ojuope lo
Ogb'oju mi lowo omije
Temitope ojuope lo
Eeeeeeee
Oluwa korede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati
Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwamayomikun o
Oluwamayomide
Ayowoletomi
Ayomiposi Oluwafemi Oluwasegunfunmi o
Oluwamimodupe
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwa korede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Of'ire gbogbo wa miri o
Of'ire wa miri
Oluwasotemidayo
Oluwasotemidire
Oluwakemi Oluwatungbemiga o
Oluwajomiloju
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwakorede
Of'ire wa mi ri
Otun fikunayo mi
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Oluwatosin
Oluwatofarati Oluwatobiloba
Temitope oo
Atofarati bi oke
Olowogbogboro
Agbanilagbatan
Temitope
Eeeee
Oro mi Tope
Temitope oo
Oluwaseun
Oluwamodupe o
Temitope
Oro mi Tope Temitope oo
Oluwaseun
Oluwamodupe o
Temitope oo
Oluwaseun
Oluwa e se o
Temitope oo
Oluwaseun
Oluwamodupe o
Temitope o
Oluwaseun
Oluwa ese o
Temitope oo
Oluwaseun
Credits
Writer(s): Felicia Kolawole
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.