Òyígíyigì Mã Gbé Ọ Ga

Òyígíyigì o
Alágbàwí ẹ'dá o
Alákòóso ọ'run
Ẹ'yin mà lológo jùlọ

Òyígíyigì o
Alágbàwí ẹ'dá o
Alákòóso ọ'run
Ẹ'yin mà lológo jùlọ

Ká tó dá aiyé
Lẹ'yìín tìín jọba
Ẹ'yin lẹ dá ẹyẹ
Ẹ'yin lẹ dá ẹranko
Ẹ'yin lẹ dá ènìyàn o
Láwòrán ara yín o o o
Ẹ'yin Lọlọ'run Baba
Ọlọ'run ọmọ
Àtẹ' Ẹ'mí-mímọ' o

Baba Òyígíyigì

Òyígíyigì o
Alágbàwí ẹ'dá o
Alákòóso ọ'run
Ẹ'yin mà lológo jùlọ

Òyígíyigì o
Alágbàwí ẹ'dá o
Alákòóso ọ'run
Ẹ'yin mà lológo jùlọ

Ògo ni f'órúkọ rẹ
Ìyìn ló yẹ ọ' o Baba
Atóbá j'aiyé
Arúgbó ọjọ'
Bí atín lọ
Bí atín bọ'
Ẹ'yin lẹ'nn tọ'jú wa
Baba mímọ'
Ògo ni f'órúkọ rẹ

Baba Òyígíyigì

Òyígíyigì o
Alágbàwí ẹ'dá o
Alákòóso ọ'run
Ẹ'yin mà lológo jùlọ

Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o
Màákọrin màá gbé ọga o



Credits
Writer(s): Clement Daniel Olabisi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link