MAJA
Maja Maja Maja
Maja Maja Maja
If dem no open door for me, e mi aja lekun
Maja maja maja o
If dem no open door for me, e mi aja lekun yi, o
Maja maja maja o
Yeah
Young makanki, I dey para
Young makanaki, I dey crase
I go change am for anybody
Anybody wey try to stop me
This big apple, I go chop am o
This little light of mine, I'm gon let it shine
Trouble dey, but I go conquer
Maja maja maja
Tẹ'níọlá, Ọmọ Simeon, Ọmọ Ọláṣebìkan
Ọmọ J'ọ'gẹ'dẹ' sunwọ'n ju onisu
Ọmọ ọ'gẹ'dẹ' lílá aborí kìjọkìjọ
Ọmọ Oká, Ọmọ Erè, Ọmọ Ọwá, Ọmọ Ẹkùn
Ǹlẹ' ò Tẹ'níọlá
Ó ró gẹ'gẹ' ó wọnú ẹgbẹ'
Ẹ'gbọ'n Tẹjúmọ'lá
Ọmọ Fọlájogún, Olúbi àrókẹ'
Ǹlẹ' ò Ẹdúlamọ', Àrà dede ṣekùn
Ùpọn kùkù súnlána ẹ' tímọ'tímọ'
Í ké bá bayà un, í á bànà un
Ọmọ ẹbọ díyé ẹwà ṣe úfẹ'ẹ' nanàá
Ọmọ lúmọlẹ' yéye gidọnẹ
Ọmọ Aládémèjì l'óǹdó
Ọmọ aládé mù, ọmọ aládé udẹ
Ọmọ ọlá oko àgbá jì yẹyẹ nínú ìṣà
Ọmọ lẹ'gungun gbọ'n wéè àpò
Ọmọ lílẹ'pọ'n bíi tadẹ'gbudọ' mú joi
Nímọ'ṣà
Ọmọ lúmọlẹ'
Ọmọ lúmọ' ìṣà lúmọ', Ọmọ Ọláṣebìkan
Ọmọ àtàkúmọ', Ọmọ lógo, Àólú
Ọmọ énusọ'
Maja Maja Maja
If dem no open door for me, e mi aja lekun
Maja maja maja o
If dem no open door for me, e mi aja lekun yi, o
Maja maja maja o
Yeah
Young makanki, I dey para
Young makanaki, I dey crase
I go change am for anybody
Anybody wey try to stop me
This big apple, I go chop am o
This little light of mine, I'm gon let it shine
Trouble dey, but I go conquer
Maja maja maja
Tẹ'níọlá, Ọmọ Simeon, Ọmọ Ọláṣebìkan
Ọmọ J'ọ'gẹ'dẹ' sunwọ'n ju onisu
Ọmọ ọ'gẹ'dẹ' lílá aborí kìjọkìjọ
Ọmọ Oká, Ọmọ Erè, Ọmọ Ọwá, Ọmọ Ẹkùn
Ǹlẹ' ò Tẹ'níọlá
Ó ró gẹ'gẹ' ó wọnú ẹgbẹ'
Ẹ'gbọ'n Tẹjúmọ'lá
Ọmọ Fọlájogún, Olúbi àrókẹ'
Ǹlẹ' ò Ẹdúlamọ', Àrà dede ṣekùn
Ùpọn kùkù súnlána ẹ' tímọ'tímọ'
Í ké bá bayà un, í á bànà un
Ọmọ ẹbọ díyé ẹwà ṣe úfẹ'ẹ' nanàá
Ọmọ lúmọlẹ' yéye gidọnẹ
Ọmọ Aládémèjì l'óǹdó
Ọmọ aládé mù, ọmọ aládé udẹ
Ọmọ ọlá oko àgbá jì yẹyẹ nínú ìṣà
Ọmọ lẹ'gungun gbọ'n wéè àpò
Ọmọ lílẹ'pọ'n bíi tadẹ'gbudọ' mú joi
Nímọ'ṣà
Ọmọ lúmọlẹ'
Ọmọ lúmọ' ìṣà lúmọ', Ọmọ Ọláṣebìkan
Ọmọ àtàkúmọ', Ọmọ lógo, Àólú
Ọmọ énusọ'
Credits
Writer(s): Moses Philip Kayode, Teni
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.