Scopatumana

Hello how are you
Otiye eh
Yung Jay Asorogbayi t'on para lowa nbí bayii oh
E sha tiri boshenlo hahaha
O loud ju loud lo Olohun
Oju mí logbo Obo mi ogbo
Brother ejo e gbé mi
Kuro nbi já japa
Shalewa tó shako simi
Moti mo pé gbogbo won lọ sí má salamo
Shout out si awọn nigga témi
Tó wà ní Bariga dé falomo

O ṣiṣe O ṣiṣe werey
Òun dúró dé Manna
Scopatumana woni bọbọ yíò ní manner
Kúrò nbi ọmọ kékeré olobo grandma
Scopatumana woni bọbọ yíò ní manner
Scopatumana Bobo yen gatz hammer
Scopatumana Bobo yen gbọ grammar
And I pulled up in a Hummer
Letter from your Mama
Wanna be my baby Mama
Scopatumana

Scopatumana Bobo o gbó grammar
Scopatumana ọmọ boy yìí gats hammer
And I pulled up in a Hummer
Letter from your Mama
Wanna be my baby Mama
Scopatumana
Fine girls fẹ jẹ banana
O fẹ lọ Bahamas
Tin ba ti drop my bars
Wa kọ má gbó
Gbìn gbìn gbà

O ṣiṣe O ṣiṣe werey
Òun dúró dé Manna
Scopatumana woni bọbọ yíò ní manner
Kúrò nbi ọmọ kékeré olobo grandma
Scopatumana woni bọbọ yíò ní manner
Scopatumana Bobo yen gatz hammer
Scopatumana Bobo yen gbọ grammar
And I pulled up in a Hummer
Letter from your Mama
Wanna be my baby Mama
Scopatumana

Ọba lón kí yín kepè ọ
Kabiyesi tíó gbà gbà kù gbà
Àgbàdá ọwọ lewo
Ilẹkẹ dolce and gabbana
Cubana Kobana
Àgbà awọ Chief priest Cubana
Òní kín bó sòkòtò
Mọ dé bó sòkòtò
Ọwá kigbe Hosanna
And I pulled up in a Hummer
Letter from your Mama
Wanna be my baby Mama
Scopatumana
Fine girls fẹ jẹ banana
O fẹ lọ Bahamas
Tin ba ti drop my bars
Wa kọ má gbó
Gbìn gbìn gbà

O ṣiṣe O ṣiṣe werey
Òun dúró dé Manna
Scopatumana woni bọbọ yíò ní manner
Kúrò nbi ọmọ kékeré olobo grandma
Scopatumana woni bọbọ yíò ní manner
Scopatumana Bobo yen gatz hammer
Scopatumana Bobo yen gbọ grammar
And I pulled up in a Hummer
Letter from your Mama
Wanna be my baby Mama
Scopatumana
Skrrrrrrrrr Skrrrrrr

Ladies and Gentlemen
Fyer



Credits
Writer(s): John Omoleh
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link