Ibere

Ibere isere lo tun laye mi
Onise ara mo dupe oo
Ibere isere lo tun lori igba mi
Ileru niyin o seun oo
Ibere isere lo tun laye mi
Onise ara mo dupe oo
Ibere isere lo tun lori igba mi
Ileru niyin o seun oo
Ibere isere lo tun laye mi
Onise ara mo dupe oo
Ibere isere lo tun lori igba mi
Ileru niyin o seun oo

Olorun oshe o Oba iyanu
Olorun oshe mo dupe o
Olorun oshe o Oba iyanu
Olorun oshe mo dupe o
Opolopo emi lo ti nu lo ti lo
O o je kin ra rinu Baba mo dupe
Otun fun mi lalafia mo rije mo rimu
Olorun oshe mo dupe o

Ore ofe re lo so mi de eniyan
Ife se to oto to ni si mi lo so mi di olori ire
Anu re lo so mi di alayo
Mimu se ileri re lo mu mi wa sho ope

Oya ma gbo Oba mi ma gbo
Ma gbo olu gbe mi ma gbo
Titi aye ni ma yin o fun anu re
Titi aye ni ma yin o fun ife re

Ibere isere lo tun laye mi
Onise ara mo dupe oo
Ibere isere lo tun lori igba mi
Ileru niyin o seun oo
Ibere isere lo tun laye mi
Onise ara mo dupe oo
Ibere isere lo tun lori igba mi
Ileru niyin o seun oo

Adeba o se o Oba iyanu
Olorun oshe mo dupe o
Alorun alaye oshe Oba iyanu
Olorun oshe mo dupe o

Opolopo emi lo ti nu lo ti lo
O o je kin ra rinu Baba mo dupe
Otun fun mi lalafia mo rije mo rimu
Olorun oshe mo dupe o

Oju esu lara mi o da asan
Opa ibanuje mi re egan mi wa di ogo
Kini mo je Olorun to fi pe mi wa shola
Ope lope re lara mi aa mo dupe
Oda ori mi lare
Oba ti kin nse etan
Oda ori mi lare
Oba ti kin nse etan
Ose ose ose ose o alayo mi fun mimu se ileri re

Ibere isere lo tun laye mi
Onise ara mo dupe oo
Ibere isere lo tun lori igba mi
Ileru niyin o seun oo

Emi lo se eyi fun tan
Olorun oseun
Emi lo se eyi fun tan o Baba mi
Olorun oseun
Egan mi di ogo Ola re ni
Olorun to shola fun mi to tun fa ayo ba mi
Oruko re ton yin olola
Emi lo se eyi fun tan
Olorun oseun
Emi lo se eyi fun tan
Olorun oseun
Egan mi di ogo Ola re ni
Olorun to shola fun mi to tun fa ayo ba mi
Oruko re ton yin olola

Ni igba ti ibanuje de
Kosi alabaro kan kan
Iwo lo wa fun mi o
Olola

Ose egan mi do ogo
Fun ogo re o so ro mi di ogo
Ti aye emi yo ma yin o oo
Eyin to so ju okan mi mo dupe

Emi lo se eyi fun tan
Olorun oseun
Emi lo se eyi fun tan
Olorun oseun
Egan mi di ogo Ola re ni
Olorun to shola fun mi to tun fa ayo ba mi
Oruko re ton yin olola



Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link