Ti Oluwa Ni Ile

Eh, eh, eh, eh
Ye, eh, ya, ah, ah
T'Oluwa Olorun ni

T'Oluwa ni ile ati ekun re
Aye ati awon to tedo sinu re (e)
O fidi re sole sori okun
Ati sori isan omi, ye

T'Oluwa Olorun ni o
T'Oluwa Olorun ni
Ah, ah, ah, ah, ah

Tani yio gori oke Oluwa lo (Oluwa lo)
Tabi tani yio duro, nibi mimo re (Mimo re o)
Awon to won ni owo mimo, ati aya funfun a
Awon ti won ko gb'okan won soke si asan (Beeni)
Ti won o si bura etan ri laye won o
Awon wonyi ni won yio ri ibukun gba ni owo Oluwa
(Ni owo Oluwa)
Ati ododo, lowo Olorun igbala won (Ah, ah)
Eyi ni iran awon ti n se aferi re o (Ah)
Tin saferi re o, Olorun agbaye o

T'Oluwa ni ile ati ekun re
Aye ati awon to tedo sinu re (e)
O fidi re sole sori okun
Ati sori isan omi, ye

T'Oluwa Olorun ni o
T'Oluwa Olorun ni
Ah, ah, ah, ah, ah

E gbori yin soke, eyin enu ona
(Eyin enu ona)
K'a gbe yin soke, eyin ilekun ayeraye
(Ayeraye o a) Eh-ah
E gbori yin soke, eyin enu ona o (Eyin enu ona)
K'a gbe yin soke, eyin ilekun ayeraye o
K'Oba ogo, ko wole wa, wa o (Ko wole wa o o)
K'Oba ogo o, ko wole wa o (Wole wa o)
Tani Oba ogo yi o (Baba mi)
Tani Oba ogo yi o o o o
Oluwa mi, to po ni ipa ati agbara, a ye
Olorun mi, to lagbara loju ogun
E gbori yin soke, eyin enu ona (Nu ona)
K'a gbe yin soke, eyin ilekun ayeraye (Ilekun ayeraye o)
E gbori yin soke, eyin enu ona o (Eyin enu ona)
K'a gbe yin soke, eyin ilekun ayeraye o (Ilekun ayeraye o)
K'Oba ogo, ko wole wa (Wa) wa
K'Oba ogo o, ko wole wa o
Tani Oba ogo yi o
Tani Oba ogo yi o
Oluwa Olodumare, Oun l'Oba ogo

T'Oluwa ni ile ati ekun re
Aye ati awon to tedo sinu re (e)
O fidi re sole sori okun
Ati sori isan omi, ye

T'Oluwa Olorun ni
T'Oluwa Olorun ni
Ah, ah, ah, ah, ah



Credits
Writer(s): Adegboyega Adeoye Ogunde
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link