Hustlers - Low Fidelity

Ọtí yẹ é bé
It's your boy Loveless
Ọtí skrrrobo skrramaryan
You know what's on my mind i always yarn
Ọmọ ajé paki ọtí d'eyan pàtàkì
Asorogbayi L'ọmọ náà
Dem call me Mr Jebejebe brother to má j'eba yín tán pátá láì sọbẹ
Oluwa Damilarey Omo Oba, Lade Vibez

Ojú tí rí tọ poverty n'bami gb'adugbo
Awọn alabosi ọrọ mí lọ fi ntà Ludo
Man never die ani ku kato d'arugbo
Èmi hustle lo efi won lẹ ẹjẹ kò má gbó
You say na blood money
Mo fun yín é ná n'be
Isi Ewu or Nkworbi
Tin ba ra e njẹ be
Now I see you know nothing about what's bugging
Keep on Hustling to make more money

Ọmọ Ọba fẹ Kí
Ọmọ Ọba fẹ Kí
Ọmọ tóun gbé ní Atẹwo
Tí wá rá lé sí Lekki
Yeah Ọmọ Ọba fẹ Kí
Ọmọ Ọba fẹ Kí
Shebi ọmọ ajé paki ọtí wà d'eyan pàtàkì
Ọmọ Ọba fẹ Kí
Ọmọ Ọba fẹ Kí
Ọmọ tóun gbé ní Atẹwo
Tí wá rá lé sí Lekki
Yeah Ọmọ Ọba fẹ Kí
Ọmọ Ọba fẹ Kí
Shebi ọmọ ajé paki ọtí wà d'eyan pàtàkì

Àlàyé olowo má f'ayọ fo
Ẹní wà nínú Benz shi le rinu erofo
Been there done that see things see me now
Where you wanna be I've been there before
Tio ba kin s'ọlọrun ṣe irú mi ma d'olowo
Ṣe irú mí lẹ di nkán t'awon olówó màmá polówó

Give me rolled blunt let's roll up some
Inspiration come anytime I take one Puff
I ain't wanna reason like the Most High
I ain't wanna sing like I'm so High

From glory to glory
Low key
Ndi a cholum eme m small kids
Haplum na uzo maka
Nga akuchi ha uzo
Adim ene anya
Abum Abuzu
Ha cho ilem office
Nga yite suit
Tomorrow we go know
Who ego suit
Hapu ndi Eji onu etinye Ose na ofe
Na ha amaro na ofe bukwa nu soup

Shẹ ọwá f'eyan mimọ soro
Ọya fi ọwọ níní j'eyan
Abosi mí lọfẹ má ṣe kà
Ọya f'ilẹ kíkọ sọrọ
Shebi talika lọ má nraye
Ẹwà wò olowo ṣe lọ n'yale
Kí l'omode mí mó àfi
Kò d'orita kàn kofi colorado pale
Bad man no dey scared to tell 'em I'm a local
Always mixing roshi and Lin in my soda
Toba wa s'orita wa ọmọ you go loyal
Tin ba ti wà gb'oja yọ
E fún mí l'omo tó tà
Ibilẹ nimi ibilẹ nimi
Akile nimi ijaya nimi
Poleti Poleti kín ní kán
Torope Ọ má retire nimi

I'm a Hustler I'm a Hustler
Everyday I'd been grinding to make my own Mula
I'm a Hustler I'm a Hustler
Grinding everyday, everyday i wan make Mula

Tutututututututu



Credits
Writer(s): John Omoleh
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link