IBADAN
(Ibadan Omo Oluyole, Ibadan Omo Oluyole ooh)
(Ibadan ko maa ni baje lai lai) Beats from P'Jay (Ibadan Omo Oluyole ooh)
(Ibadan ko maa ni baje, Ibadan Omo Oluyole ooh)
(Ibadan ko maa ni baje lai lai, Ibadan Omo Oluyole ooh)
Ibadan ni mi, Omo Oluyole ooh
Ibadan ni mi, Omo Ajorosun nnnnh
You can see it on my face
And the blood run through my vein
If you tell me say you come from Ibadan
Awa ara'wa la ri ra wa
Ibadan o ni baje l'Aiye, Ibadan o ni daru ooh
Awa l'Omo Ogunmola Iba Oluyole ooh
Awa l'Omo Ibikunle Ibadan ilu Ojo ooh
A n J'egbin J'ekarahun nnn eh
Maja, Maja, Maja, Maja ooh, a n ko won L'eru lo (Aaah)
Ibadan n m'Eru lo, Eru e n m'Eru lo (Aaah)
Ija igboro undefeated, arun kan ta ni niyen
I was born and raised up there, my Parents came from there
Je a lo Bodija, Nalende, kajo d'Eleyele
Toba gb'Akedemi de Sasa, so mo na d'Oja Oba
Ibadan saa le mo, e ranti pe o mo Layipo
Na we be the Pace Setter le se n wa te fe l'awo epo

Let go there, I take you there
Say you want to party let go there (Aaah)
Let go there, I take you there (Aaah)
And we got the money let go there (Aaah)
E lo gb'Ori wa, ke lo gb'eni wa
E wa j'Aiye ta n je ni Ibadan ooh
Ta n je ni Ibadan wo wo wo wo wo
Je a gba Liberty, Molete, k'afi ja Bere
To ba gba Felele, Mokola, So mo na d'Apata

(Ibadan Omo Oluyole, Ibadan Omo Oluyole ooh) (Omo Oluyole ooh)
(Ibadan ko maa ni baje lai lai) B Myne Sound (Ibadan Omo Oluyole ooh)
(Ibadan o ni daru ooh) (Ibadan ko maa ni baje, Ibadan Omo Oluyole ooh)

Credits
Writer(s): Aliu Waheed Adewale
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.