Jesu Loba

Jesu ran agbara si okan ese mi lati ma pa mi mo
Nitori na, mo ri ore ofe gba
Gba te mi na de, lati ma sakoso ina ife orun
Lo ngbo na ninu okan mi

Mo wole lese re, lese agbelebu mo fi ra mi rubo
E ebo ojojumo
Jesu san geese naa, o ko oruko mi sori ebo na
Ina emi o si de

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye

Ko si ise rere ti mo le fi sogo mo de ni tewo gba
Ni pa ore ofe re
Ogo ni fo lorun, korin halleluya o dana ife re
Ti o jo ninu okan mi

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye

Jesu loba, ohun loba
Jesu loba ni gbogbo aiye
Jesu loba, ohun loba ha han
Jusu loba ni gbogbo aiye



Credits
Writer(s): Babatunde Fayomi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link