Lord Lift Me Higher (Olúwa Gbémisókè) [feat. Biola]

Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Wá gbé mi lọ sí ibi gíga
Wá gbé mi lọ sí ibi gíga
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè

Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Wá gbé mi lọ sí ibi gíga
Wá gbé mi lọ sí ipò gíga
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè

Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Wá gbé mi lọ sí ibi gíga
Wá gbé mi lọ sí ibi gíga
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè

Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Wá gbé mi lọ sí ibi gíga
Wá gbé mi lọ sí ipò gíga
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè
Olúwa jọọ wá gbé mi sókè

Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe
Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe
Ìwọ tío dá ayé àtòrun, kílolèṣe
Ìwọ tío jíí òkú dìde kílolèṣe
Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe
Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe

Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe
Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe
Ìwọ tío dá ayé àtòrun, kílolèṣe
Ìwọ tío jíí òkú dìde kílolèṣe
Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe
Kílolèṣe Ọlọ'run mi, kílolèṣe

Talẹ òjùlọ? Olúwa, talẹ òjùlọ?
Talẹ òjùlọ? Bàbá mi, talẹ òjùlọ?
Ẹ'yin tí ẹdá ayé àtòrun, talẹ òjùlọ
Ẹ'yin tí ẹji òkú dìde, talẹ òjùlọ
Talẹ òjùlọ? Ọlọ'run mi, talẹ òjùlọ
Talẹ òjùlọ? Ọlọ'run mi, talẹ òjùlọ

Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse
Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse
Ìwọ tío dá ayé àtòrun, kíkolèse
Ìwọ tío jí òkú dìde kílolèse
Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse
Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse

Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse
Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse
Ìwọ tío dá ayé àtòrun, kíkolèse
Ìwọ tío jí òkú dìde kílolèse
Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse
Kílolèse Ọlọ'run mi kílolèse

Talódàbíre, Ìwọ lọba àwọn Ọba
Talódàbíre, Ìwọ tóbi jù
Mowólè níwájú Rẹ
Moyìn ọ lógo, Bàbá
Moké Hosanna, Bàbá
Moké Hosanna

Talódàbíre èwọ lọba àwọn ọba
Talódàbíre èwọ tóbi jù
Mowólè síwájú rẹ
Moyìn ọ lógo bàbá
Moké hosanna bàbá
Moké hosanna

Talódàbíre èwọ lọba àwọn ọba
Talódàbíre èwọ tóbi jù
Mowólè níwájú rẹ
Moyìn ọ lógo bàbá
Moké hosanna bàbá
Moké hosanna

Òyígíyigì o o o
Alágbàwí ẹ'dá a a
Alákoso ọ'run
Ẹ'yin mà lológo jùlọ

Òyígíyigì o o o
Alágbàwí ẹ'dá
Alákoso ọ'run
Ẹ'yin mà Lológo jùlọ

Òyígíyigì o o o
Alágbàwí ẹ'dá
Alákoso ọ'run
Ẹ'yin mà Lológo jùlọ

Òyígíyigì o o o
Alágbàwí ẹ'dá
Alákoso ọ'run
Ẹ'yinmà Lológo jùlọ

Òyígíyigì o o o
Alágbàwí ẹ'dá
Alákoso ọ'run
Ẹ'yin mà Lológo jùlọ

Òyígíyigì o o o
Alágbàwí ẹ'dá
Alákoso ọ'run
Ẹ'yin mà Lológo jùlọ



Credits
Writer(s): Clement Olabisi Daniel
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link