Iwo Ga

Ohun Oluwa ni agbara, O ni agbara
Ohun Oluwa n san ara lori'san omi
Ohun Oluwa fagi araba ya o o
O ga, Baba ga ju
O ga ju gbogbo won lo

Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa kabikabi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa rebirebi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa runbirunbi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa kabikabi

Owo Oluwa ni a gbe ga, oun la gbe ga
Owo t'o n sise agbara, t'o n sise agbara
Owo to pin okun niya o o o
O ga, Baba ga ju
O ga ju gbogbo won lo

Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa kabikabi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa rebirebi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa runbirunbi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa kabikabi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa rebirebi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa runbirunbi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa kabikabi
Iwo ga ju gbogbo won lo
Alapa kabikabi

O ga, Baba ga ju
O ga ju gbogbo won lo

Ta lo n je ode afifilapa-erin niwaju ode afifilapa-eyan
O ga, Baba ga ju
O ga ju gbogbo won lo

E ju won lo
Baba mi
E ju won lo
Kabiesi
E ju won lo
Baba mi
E ju won lo
Kabiesi
E ju won lo
Baba mi
E ju won lo



Credits
Writer(s): Ayobami Kehinde
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link