The Snitcher
Afolabi adura re o gba,
Bi omo araye se maa jeran Mecca lodoodun,
Gbogbo Eda tii Olohun fii owo re da
won o maa jeran re Siti daada ni o,
Okan re o bale,
Omo araye oni tapo sa Ala re o,
Oniyangi epo naa ru won oni da epo sa Ala re o,
Ogo re o buyo
ode bii ise logo re o,
Adura re yoo gba ni gbogbo ona
wola lahola wala Kuwata ila.
Yan he yan yan he Ye
Balo Gold O
Robotiki robotika
he yen hun o hun o o hun o.
Oni Yangi Matapo sala mii
sala mii
Sala mi
Aso fun fun ti mo ro waye kaye mata po sii
Kaye maa tapo sii
Oluwa mii
je n debi ola mii ola mii
Ola mii
maami tii sadura fun mi pe wasere omo mii
Oni Yangi Matapo sala mii
sala mii
Aso fun fun ti mo ro waye
kaye mata po sii
Oluwa mii je n debi ola mii
ola mii
maami tii sadura fun mi pe wasere omo mii
Sebi eyin lefun mii lounje kilode tetun fe kin yoo
Sebi eyin le kole fun mi Kilode te tun fe kii maa gbe gbo
Araye buru gaan
Won ni ka
Won fe Kani laari
Me no wish anybody bad o
Ire akari
(Ahhh Oniyangi ebe mo be o ebe mo be o)
(Ahhh n ahhh Oniyangi ebe mobe o ebe mo be o)
Oma Dara fun mii
Oma Dara fun wo
Kato Leri omo lakeji taa sobe oma pee gann
Oma Dara fun mii
Oma Dara fun wo
Me no wish anybody bad o
Ama nii laari
(Ahhh Oniyangi ebe mo be o ebe mo be o)
(Ahhh n ahhh Oniyangi ebe mobe o ebe mo be o)
Ahhh mama mii
Oni sunkun
Laye
Ahhh oloko mii
Ose towami waye
Ahh oniyangi
Mapa iya mii lekun
Ahhh oluwa mii maje iya mii sunkun o
Baba mi ajere mii
Iya mii ajere mii
Shey bi Awon naa shise o
Dan Dan ni kon ko ere ooo
Ti isu omo ba jina koma shey jowon lenu
Yeh yeh e e
O o hun
Gold boy! Gold boy!
Bi omo araye se maa jeran Mecca lodoodun,
Gbogbo Eda tii Olohun fii owo re da
won o maa jeran re Siti daada ni o,
Okan re o bale,
Omo araye oni tapo sa Ala re o,
Oniyangi epo naa ru won oni da epo sa Ala re o,
Ogo re o buyo
ode bii ise logo re o,
Adura re yoo gba ni gbogbo ona
wola lahola wala Kuwata ila.
Yan he yan yan he Ye
Balo Gold O
Robotiki robotika
he yen hun o hun o o hun o.
Oni Yangi Matapo sala mii
sala mii
Sala mi
Aso fun fun ti mo ro waye kaye mata po sii
Kaye maa tapo sii
Oluwa mii
je n debi ola mii ola mii
Ola mii
maami tii sadura fun mi pe wasere omo mii
Oni Yangi Matapo sala mii
sala mii
Aso fun fun ti mo ro waye
kaye mata po sii
Oluwa mii je n debi ola mii
ola mii
maami tii sadura fun mi pe wasere omo mii
Sebi eyin lefun mii lounje kilode tetun fe kin yoo
Sebi eyin le kole fun mi Kilode te tun fe kii maa gbe gbo
Araye buru gaan
Won ni ka
Won fe Kani laari
Me no wish anybody bad o
Ire akari
(Ahhh Oniyangi ebe mo be o ebe mo be o)
(Ahhh n ahhh Oniyangi ebe mobe o ebe mo be o)
Oma Dara fun mii
Oma Dara fun wo
Kato Leri omo lakeji taa sobe oma pee gann
Oma Dara fun mii
Oma Dara fun wo
Me no wish anybody bad o
Ama nii laari
(Ahhh Oniyangi ebe mo be o ebe mo be o)
(Ahhh n ahhh Oniyangi ebe mobe o ebe mo be o)
Ahhh mama mii
Oni sunkun
Laye
Ahhh oloko mii
Ose towami waye
Ahh oniyangi
Mapa iya mii lekun
Ahhh oluwa mii maje iya mii sunkun o
Baba mi ajere mii
Iya mii ajere mii
Shey bi Awon naa shise o
Dan Dan ni kon ko ere ooo
Ti isu omo ba jina koma shey jowon lenu
Yeh yeh e e
O o hun
Gold boy! Gold boy!
Credits
Writer(s): Balogun Basit
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.