Ori Lo Mo

Masa mi kuri fana
Mo ri ire o

Gone are the days my papa used to tell me that we are the future
I've been searching
I'm still searching
Mo r'okun mo r'osa o

Se b'ori lo mo
Se b'ola lo mo
Bo ya ma de ibi giga ori lo mo o

Se b'ori lo mo
Se b'ola lo mo
Bo ya ma di eniyan l'ola ori lo mo

I'm a pilot in my Country
Everybody knows me well
If you look at me up and down
You will know that it's true

Awon omo alaigboran po ni ile iwe
Wo ki f'eti sile lati gbo t'oluko won
B'oluko ni kan ka iwe won a si ma se ere ka
Won a jeun jeun jeun
Won a gb'ofo roboto

Ise ise ise ise Iyen kii se ti won
Ere ere ere ere
Iyen sa ni ti won
Dodo ati rice
Ko gbodo koja
Won a jeun jeun jeun
Won a gb'ofo roboto

Se b'ori lo mo
Se b'ola lo mo o
Bo ya ma de ibi giga
Ori lo mo o

Se b'ori lo mo
Se b'ola lo mo
Bo ya ma d'eniyan l'ola
Ori lo mo o

Bata mi n dun ko ko ka

Bata mi n dun ko ko ka
Tori mo ka iwe mi
Bata mi n dun ko ko ka
Iwo na ka iwe re
Bata re a dun ko ko ka

Emi a r'oko
Emi a r'oko
Emi a r'oko fun mama mi o l'aye yi
Bata mi a dun ko ko ka

Emi a r'oko
Emi a r'oko
Emi a r'oko fun mama mi o l'aye ye o oh
Emi a ra moto
Emi a ra moto
Emi a ra moto
Emi a ra moto



Credits
Writer(s): Ademola Adeleke
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link