Ojonlo

Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo
Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo
Akoko ko ma duro
'wo to'n f'igbala d'oni
'wo to'n f'igbala d'ola
'wo to'n f'igbala fa'le
Ojonlo
Jowo ma jafara
Tete se ki'o ro'nu igbeyin aiye
B'oni ti ri, ola ko ri be
Bi o ba se se se, to ko Jesu sile
Bi o ba b'aiye lo, to lo gbe lukudi
To ba wa d'igbeyin aiye, to be wa so emi re nu
Asenu re yio ti po to
Ko s'ebo fun asenu, ko s'ebo fun asenu, alaigboran
Ko s'ebo fun asenu, ko s'ebo fun asenu, iwo alaigboran



Credits
Writer(s): Akinade Ibuoye
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link