Money Talk

Aremo Kuti (Gaza)
Omo Fela na ni oo

Tinba ti gbowo moma shomo
Yogurt jor spam kole domo
Aremo Kuti o moo rap, maa somo
Mo nsise fun owo mi, ise opolo
Ohun lo amudo, emi lo loud monfi shomo
Moti fa loud yoh oo, emi o gbo nkankan mo
Won ni kinni mofe, mofe owo, mofe ola
Wole mi kuro ninu ile won, won lemi sola

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

O somi di calculator, o fema text mi
O fema f'oti adugbo won ma oppress mi
O somi di koorlu, o fema press mi
On a Canadian level, wa light mi
Scro! Scro!! like Motor
Scro! Scro!! like Huncho
Kawa meji soke, bi Fela Kuti
My name is Aremo Kuti

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo

Eti mi tidi, mi o gbo nkankan mo
Oro Owo ni mogbo, mi o gbo nkankan mo



Credits
Writer(s): Damilola Aremo Kuti
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link