Omi Iye

Gbogbo eni oungbe n gbe
E wa o e wa o
Sibi omi iye lofe
Jesu lomi iye fun araye
Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Jesu wipe e wa sodo mi
Gbogbo eyin to n sise
Taye di eru wiwo le lori
To n se laala nitori ounje
Won sise lafemojumo d'oganjo
Awe funfun awe pupa f'ona abayo
Mo ti ri Jesu to le tan oungbe re
A te o lorun yara wa
Ajaga tire lo rorun o
Eru Jesu lo fuye

Gbogbo eni oungbe n gbe
E wa o e wa o
Sibi omi iye lofe
Jesu lomi iye fun araye
Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Ebi ton pa'ye ounje o le tan
Oungbe to n gbe aye o o ju t'omi lo
Jesu lo n yo ni ara re lounje
Eje re loun mimu tooto
Ma ra eyi ti kii se ounje mo
Ma ra eyi ti kii s'aso o
Wa sodo Jesu A bo 'hoho re
Ko to goke adura wa igbala ri
Wa sodo Jesu A ba o se
Igbala ofe Re lona abayo o

Gbogbo eni oungbe n gbe
E wa o e wa o
Sibi omi iye lofe
Jesu lomi iye fun araye
Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Obinrin samaria leti kanga
O fe pon omi omi to maa tan
Sugbon o wa pade Olomi iye
Jesu wipe to ba mu ninu mi
Oungbe o ni gbe o mo lai
Kanga aye ungbe orun aye npani
Ma ma sa kiri mo ore mi
Wa sodo Jesu ko le ni simi
Oluwa lo le fun o layo o
Wa sodo Jesu ko le ni simi

Gbogbo eni oungbe n gbe
E wa o e wa o
Sibi omi iye lofe
Jesu lomi iye fun araye
Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o

Ounje fokan tebi n pa
Jesu ni o e ma bo o...



Credits
Writer(s): Adebukola Olayinka Regina
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link