Oore Ọ̀fẹ́

Oore ofe wa mi ri
(Your Grace found me)
Oore ofe gba mi là
(Your Grace saved me)
Oore ofe mu mi de'le
(Your Grace takes me home)
Nígbàtí mo ri'na subu
(Even if I should fall)
Oore ofe lo gbe mi ro
(Your Grace upholds me)
Oore tó fún mi
(Your Grace is sufficient for me)

Mo wa dupẹ, ibití mo ti bere
(I've come to thank you for my beginning)
Gba mo ronú ibiti mo ba dé
(When I think of where you have brought me)
Mo wa dupẹ, ibití mo ti bere
(I've come to thank you for my beginning)
Gba mo ronú ibiti mo ba dé
(When I think of where you have brought me)

Ọpẹ mi ye oo, Jésù
(You deserve my praise, Jesus)
Gbogbo ọpẹ lo yẹ o
(You deserve all the Praise)
Ọpẹ mi ye ọ o,Jésù
(You deserve my praise, Jesus)
Gbogbo ọpẹ lo yẹ o
(You deserve all the Praise)

B'emi o ba dupẹ
Mo y'alaimore eniyan
Mo y'alaimore eniyan
Mo y'alaimore oo
B'emi o ba dupẹ
Mo y'alaimore eniyan
Mo y'alaimore eniyan
Mo y'alaimore oo

Mo wa dupẹ, ibití mo ti bere
(I've come to thank you for my beginning)
Gba mo ronú ibití e mu mi de
(When I think of where you Have brought me)
Mo wa dupẹ, ibití mo ti bere
(I've come to thank you for my Beginning)
Gba ti mo ri ibití a mu mi de
(When I think of where you Have brought me)

Ọpẹ mi ye oo, Jésù
(You deserve my praise, Jesus)
Gbogbo ọpẹ lo yẹ o
(You deserve all the Praise)
Ọpẹ mi ye ọ o,Jésù
(You deserve my praise, Jesus)
Gbogbo ọpẹ lo yẹ o
(You deserve all the Praise)

B'emi o ba dupẹ
Mo y'alaimore eniyan
Mo y'alaimore eniyan
Mo y'alaimore oo

Oore ofe wa mi ri
(Your Grace found me)
Oore ofe gba mi là o
(Your Grace saved me)
Oore ofe mu mi de'le
(Your Grace takes me home)
Nígbàtí mo ri na subu
(Even if I should fall)
Oore ofe lo gbe mi ro
(Your Grace upholds me)
Oore tó fún mi
(Your Grace is sufficient for me)



Credits
Writer(s): Adeyemi Opeyemi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link