Olori Aye mi

Olu orun
Mo m'ope mi wa
Adani ma gba gbe
Igba ope mi re
Ore t'e se fun mi
Ko lalafiwe
Emi m'ore re
Ore ofe re yi ti poju

Nigba ti m'oku ninu ese
Ninu ese
O faye at'eje re ra mi pada o
O wo nu okan mi
O fi mi se ibugbe re
O de so mi domo

Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare
Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare

This is a song of gratitude
To the one who loves both me and you
No other attitude
To have
The one who gave it all away
Just to be so close to you and me
No other love will do
No one
O wo nu okan mi
O fi mi se ibugbe re
O de so mi domo

Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare
Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare
Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare

I'm grateful, you made me a son
A union with the three in one
In you I have a link to the father
Abba father
A life truly everlasting
You provide for everyone who
Believes in you for salvation
Oluwa

Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare
Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare
Olori aye mi mo fe o pupo o
Alagbara nla kabiyesi
Ife re fun mi lo ramipada o
Ogo at'ola fun Eledumare



Credits
Writer(s): Emmanuel Adeniran, David Ijaduola, Bode Nathaniel
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link